Jump to content

Catherine Zeta-Jones

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Catherine Zeta-Jones
Zeta-Jones at the 2012 Tribeca Film Festival
Ọjọ́ìbíCatherine Zeta Jones
25 Oṣù Kẹ̀sán 1969 (1969-09-25) (ọmọ ọdún 55)
Swansea, Wales, United Kingdom
Orílẹ̀-èdèBritish
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1981–present
Olólùfẹ́Michael Douglas
(m. 2000–present)
Àwọn ọmọ2

Catherine Zeta-Jones, CBE, (play /ˈztə/; oruko abiso Catherine Zeta Jones; 25 September 1969) je osere ara Welsi to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo ati Ebun Tony.

Igbesi Aye Arabinrin naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Abi Catherine si Swansea, Arabinrin naa gbero lati jẹ óṣèrè lobinrin lati kekere nibi ti o ti kopa ninu Akojọpọ west end orin Annie ati Bugsy Malone[1]. Nitoripè Catherine jẹ ọmọ to jafafa, iya rẹ ran lọ si Ilè ẹkọ Hazel Johnson to dale óri ijó nigba ti o pè ọmọ ọdun mẹrin[2]. Óṣèrè lobinrin naa kẹkọ ni Ilẹ iwe Arts ni ilẹ london lori èrè oritage orin ti o si bẹrẹ sini kopa ni èrè oritage ni ọdun 1987 ninu èrè "42nd Street".

Yatọsi jijẹ óṣèrè, arabinrin naa tun kopa ninu riran awọn alaini lọwọ. Óṣere naa jẹ Patron fun Longfields ilu Swansea to da lori awọn akanda. Catherine ta aṣọ ti ó wọ ninu ọkan ninu awọn ere rẹ "Mark of Zorro" lati fi kó òwó jọ fun awọn to ni arun kogbogun AID ni ilẹ Afirica[3]. Zeta naa fẹ óṣere lọkunrin Michael Douglas ti o si bi ọmọ meji[4].

Ami Ẹyẹ ati Idani lọla

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Fun ikopa arabinrin naa ninu Chicago ti ọdun 2002, Zeta gba ami ẹyẹ ti óṣere screen guild ati ami ẹyẹ Bafta fun óṣèrè to rani lọwọ ju[5]. Ni ọdun 2019, Catherine ni a fi jẹ̀ Ọgà Apaṣẹ ti British Empire latari óṣèrè ti o jẹ ati iran lọwọ fun alaini[6].