Jump to content

Rachel Weisz

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use British English

Rachel Weisz
Weisz in 2018
Ọjọ́ìbíRachel Hannah Weisz[1]
(1970-03-07)7 Oṣù Kẹta 1970 or 1971 (age 53–54)
Westminster, London, England
Orúkọ mírànRachel Weisz Craig[2]
Ọmọ orílẹ̀-èdè
  • United Kingdom
  • United States
Iléẹ̀kọ́ gígaTrinity Hall, Cambridge
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1992–present
Olólùfẹ́
Daniel Craig (m. 2011)
Àwọn ọmọ2
Àwọn olùbátanMinnie Weisz (sister)
AwardsFull list

Rachel Hannah Weisz ( /vs/ ;[3] wọ́n bí ní ọjọ́ kéje oṣù kẹ́ta ọdún 1970 tàbí 1971)[note 1] ó jẹ́ Òsèrè Gẹ̀ẹ́sì. Ó gbà àwọn Àwọ́ọ̀dù bíi an Àwọ́ọ̀dù Akadẹ́mì, Golden Globe Award, Screen Actors Guild Award, Laurence Olivier Award, Critics' Choice Award àti BAFTA Award.

Weisz bẹ̀rẹ̀ sí ní má ṣeré ní orí ìtàgé ìlú aya-ọba àti ní tẹlẹfísọ̀n ní ọdún 1990s, àti kọ́kọ́ ṣé àfihàn rẹ̀ àkọ́kọ́ ní Death Machine (1994). Ó gbà àwọ́ọ̀dù Critics' Circle Theatre Award fún ipa rẹ̀ eré tí wọ́n tún ṣe ní ọdún 1994 eré Noël Coward tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Design for Living àti wí pé ó ṣe àfihàn ní ọdún 1999 ní eré tí ilé-iṣẹ́ Donmar Warehouse gbé jáde eré Tennessee Williams tó pè ní Suddenly, Last Summer. Nǹkan tó fi gbajúmọ̀ ní ipa tó kó gẹ́gẹ́ bí Evelyn Carnahan ní fíìmù The Mummy (1999) àti The Mummy Returns (2001).[4] Weisz lọ di olórí Òṣèré ní ọ̀pọ̀ fíìmù ní ọdún 2000 wálẹ̀ ní àwọn fìímù bíi Enemy at the Gates (2001), About a Boy (2002), Constantine (2005), The Fountain (2006) àti The Lovely Bones (2009).

Fún ipa ribiribi tó kó ní fíìmù ọdún 2005 The Constant Gardener, ó gba àwọ́ọ̀dù Academy Award for Best Supporting Actress, àti fún ipa rẹ̀ ní eré Blanche DuBois tí 2009 tí wọ́n pè ní A Streetcar Named Desire, ó gba àwọ́ọ̀dù Laurence Olivier Award for Best Actress. Ní ọdún 2010 wálẹ̀, Weisz ṣe gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe ń ṣe tẹ́lẹ̀ láti ma jẹ́ lára àwọn olórí ní àwọn fíìmù tó ń sẹ bíThe Bourne Legacy (2012) àti fíìmù Oz the Great and Powerful (2013), àti wí pé àwọn ènìyàn bú u fún ipa tó kó ní àwọn fíìmù mìíràn bí The Deep Blue Sea (2011), Denial (2016), and The Favourite (2018). Fún ipa tó kó ní Sarah Churchill, ó gba àwọ́ọ̀dù BAFTA Award for Best Actress in a Supporting Role àti wí pé wọ́n yànná fún Akadẹ́mì Àwọ́ọ̀dù kejì.[5] ní ọdún 2021, Weisz ṣe Melina Vostokoff ní fíìmù Marvel Cinematic Universe Black Widow.

Weisz fẹ́ ẹni tó ṣe fíìmù tó orúkọ rẹ̀ ń jẹ́Darren Aronofsky, tí àwọn méjèèjì ní ọmọ kan , láti ọdún 2005 sí ọdún 2010. Ó fẹ́ Òṣèré Daniel Craig ní 2011, tí wọ́n ní ọmọ obìnrin , àti wí pé ó di ara US ni ọdún yẹn bákan náà.[6]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti àwọn ẹbí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Rachel Hannah Weisz[1] ní ọjọ́ kéje oṣù kẹ́ta ọdún 1970 tàbí ọdún 1971 ní Westminster, Lọ́ndọ̀dù, ó dàgbà sí Hampstead Garden Suburb.[7] bàbá rẹ̀, George Weisz (1929–2020), Jẹ́ Ẹniginíà Hungarian Jewish.[8][9] ìyá rẹ̀, Edith Ruth (tí wọ́n bí ní Teich; 1932–2016),[10] jẹ́ tíṣà tọ́ padà sigikotẹ́rápísì làti Vienna, Austria.[11][12] àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì lọ sí United Kingdom ní ọmọdé bí ọdún 1938, síwájú kí World War II tó ṣẹlẹ̀ láti sá fún àwọn Nazis.


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Rubinstein, W.; Jolles, Michael A. (2011). "Weisz, Rachel". The Palgrave Dictionary of Anglo-Jewish History. Palgrave Macmillan. ISBN 978-0-230-30466-6. 
  2. "The Royal Theatrical Support Trust people". Companies House. 
  3. Landman, Kyle (5 August 2009). "Rachel Weisz Is Going to Start Correcting People on How to Pronounce Her Last Name". New York. https://nymag.com/daily/intel/2009/05/rachel_weisz_is_going_to_start.html. 
  4. "Weisz's breakthrough to acclaim". BBC News. 17 January 2006. http://news.bbc.co.uk/2/hi/entertainment/4619832.stm. 
  5. Tuesday; January 22 (22 January 2019). "Rachel Weisz and Richard E Grant score Oscar nominations". www.irishexaminer.com. Archived from the original on 9 February 2019. Retrieved 7 February 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  7. Aslet, Clive (14 April 2007). "Design for living". The Daily Telegraph (London). https://www.telegraph.co.uk/portal/main.jhtml?view=DETAILS&grid=&xml=/portal/2007/04/14/nosplit/fthamstead114.xml. 
  8. Applebaum, Stephen (20 January 2017). "'No denying my heritage' Stephen Applebaum interviews Rachel Weisz". The Jewish Chronicle. Retrieved 18 May 2018. 
  9. Brown, Mick (1 August 2009). "Rachel Weisz talks about starring in A Streetcar Named Desire". The Daily Telegraph. https://www.telegraph.co.uk/culture/theatre/theatre-features/5931197/Rachel-Weisz-talks-about-starring-in-A-Streetcar-Named-Desire.html. 
  10. England and Wales, Death Index, 2007–2017
  11. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named thisislondon
  12. "Rachel Weisz: 5 things to know about Daniel Craig's new wife". CBS News. https://www.cbsnews.com/8301-31749_162-20074657-10391698.html. 


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "note", but no corresponding <references group="note"/> tag was found