Guinea-Bissau
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Guinea-Bissau Republic of Guinea-Bissau República da Guiné-Bissau
| |
---|---|
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Bissau |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Portugi |
Lílò regional languages | Crioulo |
Orúkọ aráàlú | Bissau-Guinean(s)[1] |
Ìjọba | Orile-ede olominira sistemu aare die |
• Aare | Umaro Sissoco Embaló |
Rui Duarte de Barros | |
Ilominira latodo Portugal | |
• Fifilole | 24 Osu Kesan, 1973 |
• Didamo | 10 Osu Kesan, 1974 |
• Ojo Ajodun Orile-ede | 24 Osu Kesan 24 |
Ìtóbi | |
• Total | 36,125 km2 (13,948 sq mi) (136th) |
• Omi (%) | 22.4 |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 1,647,000[2] (148th) |
• 2002 census | 1,345,479 |
• Ìdìmọ́ra | 44.1/km2 (114.2/sq mi) (154th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $1.720 billion[3] |
• Per capita | $1,068[3] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $826 million[3] |
• Per capita | $512[3] |
Gini (1993) | 47 high |
HDI (2007) | ▲ 0.396 Error: Invalid HDI value · 173rd |
Owóníná | West African CFA franc (XOF) |
Ibi àkókò | UTC+0 (GMT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | 245 |
Internet TLD | .gw |
Guinea-Bissau tabi Orile-ede Olominira ile Guinea-Bissau (pípè /ˈɡɪni bɪˈsaʊ/; Pọrtugí: República da Guiné-Bissau, pípè [ʁɛˈpublikɐ dɐ ɡiˈnɛ biˈsaw]) budo si Iwoorun Afrika. O ni bode mo Senegal ni ariwa, ati Guinea ni guusu ati ilaorun, ati mo Okun Atlantiki ni iwoorun.
Aala ile re to 37,000 square kilometres (14,000 sq mi) pelu awon olugbe ti idiye won to 1,600,000.
Guinea-Bissau je ara ileoba Gabu nigbakan, to je apa Ileobaluaye Mali; awon apa ileoba wa titi di orundun kejidinlogun, nigba ti awon miran si je apa Ileobaluaye Portugal. Nigba na lo wa di ibiamusin Portugal toruko re unje Guinea Portugi ni orundun 19. Leyin ilominira, to je fifilole ni o̩dún 1973 to si je didamo ni o̩dún 1974, oruko oluilu re, Bissau, je fifikun mo oruko orile-ede lati dena iaru po mo Orile-ede Olominira ile Guinea.
14% nikan ni awon olugbe ti won mo ede onibise, Portugi so. Awon 44% nso Kriol, ede to da lori Portugi, awon yioku nso awon ede abinibi Afrika. Awon esin kanka ibe ni esin Islam ati awon esin ibile Afrika.
O je omo egbe Isokan Afrika, Agbajo Okowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika, Agbajo Ipejo Onimale, Isokan Latini, Agbajo awon Orile-ede Ede Portugi, La Francophonie ati South Atlantic Peace and Cooperation Zone.
Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè tenikookan re je ikan larin awon tokerejulo lagbaye.
Itan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilominira
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Iselu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon agbegbe ati apa ile Guinea-Bissau
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Guinea-Bissau je pipin si awon agbegbe mé̩jo̩ ati apa ibi aladawa kan. Awon wonyi na tun wa je pinpin si apa metadinlogoji. Awon agbegbe ohun niyi:
* autonomous sector |
Jeografi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon ilu pataki
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Cities in Guinea-Bissau | |||||
---|---|---|---|---|---|
Rank | City | Population | Region | ||
1979 Census | 2005 estimate | ||||
1 | Bissau | 109,214 | 388,028 | Bissau | |
2 | Bafatá | 13,429 | 22,521 | Bafatá | |
3 | Gabú | 7,803 | 14,430 | Gabú | |
4 | Bissorã | N/A | 12,688 | Oio | |
5 | Bolama | 9,100 | 10,769 | Bolama | |
6 | Cacheu | 7,600 | 10,490 | Cacheu | |
7 | Bubaque | 8,400 | 9,941 | Bolama | |
8 | Catió | 5,170 | 9,898 | Tombali | |
9 | Mansôa | 5,390 | 7,821 | Oio | |
10 | Buba | N/A | 7,779 | Quinara | |
11 | Quebo | N/A | 7,072 | Quinara | |
12 | Canchungo | 4,965 | 6,853 | Cacheu | |
13 | Farim | 4,468 | 6,792 | Oio | |
14 | Quinhámel | N/A | 3,128 | Biombo | |
15 | Fulacunda | N/A | 1,327 | Quinara |
Ojuojo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okowo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aworan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]-
BCEAO Bissau
-
BCEAO Bissau
-
Bus in downtown Bissau
-
Che Guevara Square
-
Residential area in Bissau
-
Carnival in Bissau
Demografiki
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon eya eniyan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ede
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Esin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilera
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eko
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Asa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Orisun
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Joshua B. Forrest, Lineages of State Fragility. Rural Civil Society in Guinea-Bissau (Ohio University Press/James Currey Ltd., 2003).
- Richard Andrew Lobban, Jr. and Peter Karibe Mendy, Historical Dictionary of the Republic of Guinea-Bissau, third edition (Scarecrow Press, 1997) ISBN 0-8108-3226-7 (includes extensive bibliography)
Ijapo lode
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Government
- Official government website
- Chief of State and Cabinet Members Archived 2009-10-26 at the Wayback Machine.
- Constitution of the Republic of Guinea-Bissau Archived 2011-07-25 at the Wayback Machine.
- Awifun gbogbogbo
- Link collection related to Guinea-Bissau on bolama.net Archived 2016-03-04 at the Wayback Machine.
- Country Profile from BBC News
- Àdàkọ:CIA World Factbook link
- Guinea-Bissau from UCB Libraries GovPubs
- Guinea-Bissau at Encyclopædia Britannica
- Àdàkọ:Dmoz
- Àdàkọ:Wikiatlas
- Before Project has a lot of information on the history of political violence and how it has been overcome
- Iroyin
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Background Note: Guinea-Bissau". US Department of State. December, 2009. Retrieved 7 February 2010. Check date values in:
|date=
(help) - ↑ Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 "Guinea-Bissau". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.
- ↑ CIA the World Factbook
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedEB
- Pages with reference errors
- CS1 errors: dates
- Articles containing Pọrtugí-language text
- Country articles requiring maintenance
- Pages using infobox country with unknown parameters
- Pages using infobox country or infobox former country with the symbol caption or type parameters
- Webarchive template wayback links
- Guinea-Bissau
- Pages using ISBN magic links