Jump to content

Private university

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa private universities and colleges that are academic degree-awarding. Fún primary or preparatory schools, ẹ wo: Independent school.
Harvard University, a private Ivy League university in Cambridge, Massachusetts and the first university established in the United States

Private universities (ilé ẹ̀kọ́ aládani) higher education tí kò jẹ́ dídá sílè láti ọwọ́ ìjọba governments tàbí tí wọn ò mójú tó tàbí fún ní owó. Ṣùgbọ́n, ìjọba máa ń mójú kúrò fún wọn ní ibi owó ìjọba tax breaks, àwọn ọmọ wọ́n lè yá owó ilé ẹ̀kọ́ lọ́wọ́ ìjọba àti àwọn ìrànlọ́wọ́ ìjọba. Ní àwọn ìlú kan, ilé ẹ̀kọ́ gíga aládani lè gbà ìmójútó lábẹ́ àwọn òfin ìlú òun. A lè fi ilé ẹ̀kọ́ gíga aládani wé àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga tí ìjọba tí ìjọba ni, tí wọn ń mójú tó, tí wọn sii fún ní owó. Púpò nínú àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga aládani ní wọn ń ṣiṣẹ́ láìsí èròńgbà láti jẹ èrè.

Àwọn ìlú oríṣiríṣi ní àwọn oríṣiríṣi òfin tí ó ń mójú tó dídá ilé ẹ̀kọ́ gíga aládani sílè. Nítorí ìdí èyí, àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga aládani máa ń pọ̀ ní àwọn ìlú kan ju àwọn míràn lọ. Kódà, àwọn orílè-èdè míràn ò ní ilé ẹ̀kọ́ gíga aládani rárá.