Oluseyi Makinde
Oluseyi Abiodun Makinde | |
---|---|
Gomina Ipinle Oyo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 29, 2019 | |
Asíwájú | Abiola Ajimobi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oluwaseyi Abiodun Makinde 25 Oṣù Kejìlá 1967 Ibadan |
Aráàlú | Nigerian |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Tamunominini Makinde |
Àwọn ọmọ | 3 |
Ìyá | Abigail Makinde [citation needed] |
Bàbá | Olatubosun Makinde [citation needed] |
Education | University of Lagos |
Occupation | Politician, Engineer |
Known for | Group Managing Director of Makon Group Limited |
Olusèyí Abiọ́dún Mákindé ni a bí ní ọjọ́ Karùndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1967 (25 December 1967). Ó jẹ́ oníṣòwò, olóṣèlú àti ọlọ́rẹ àtinúwá Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni Gómìnà tí ó ń bẹ lórí àléfà lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́[1] ní apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Wọ́n dìbò yàn-án ní Ọdún 2019 lábé àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party (PDP) Ó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ nípa ìwọ̀n epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì (fluid and Gas Metering).[3]
Ibere pepe aye re ati eko
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi makinde si ile Pa Olatubosun Makinde, ati Abigail Makinde ni adugbo Aigbofa, Oja’ba, ni ilu Ibadan, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ọ̀un ni awon obire bi siketa.[2][3] Makinde bere eko re ni Ile eko-ibere St Paul primary school. O pari eko- Ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ni St Michael Primary School,ni Ye metu. Makinde se eko girama ní Bishop Phillips Academy[4]. Ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásitì ìlú Èkó níbi tó ti gba ìwé-ẹrí bachelor degree nínú ìmò Electrical Engineering.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.vanguardngr.com/2019/03/oyo-guber-pdp-clears-28-lgs-to-dislodge-apc-as-makinde-emerges-gov-elect/amp/
- ↑ 2.0 2.1 "Nigeria: Makinde - Profile of Oyo Guber PDP Aspirant". allafrica.com. 21 September 2014. http://allafrica.com/stories/201409220019.html. Retrieved 21 May 2016.
- ↑ 3.0 3.1 BISI, OLADELE (23 December 2015). "Oyo 2015: Four Ibadan indigenes for governor". The Nation Online NG. http://thenationonlineng.net/oyo-2015-four-ibadan-indigenes-governor/. Retrieved 21 May 2016.
- ↑ "ICONS: Seyi Makinde". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-12-29. Retrieved 2022-03-01.