Jump to content

Nollywood

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán àwọn oniṣẹ́ sinema tó ń ya fíìmù
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa orúkọ yìí tí ṣe Nollywood. Fún fún àlàyé kíkún lórí Ilé Iṣẹ́ Fíìmù tí Nàìjíríà, ẹ wo: Cinema ti Nàìjíríà.

Àdàkọ:Use Nigerian English

Àdàkọ:Àṣà ilẹ̀ Nàìjíríà Nollywood, Èyí jẹ́ àkàǹpọ̀ orúkọ Nigeria àti Sinimá orílẹ̀-èdè America ti wọ́n mọ̀ sí Hollywood, tí orúkọ rẹ̀ sí ń kọ́kọ́ jẹ́ Sinimá tí orílè èdè Nàìjíríà tàbí ilé iṣé fíìmù Nàìjíríà.[1] Ìpilẹ̀ṣẹ̀ tí a lè ṣe ìtọpinpin fún ọ̀rọ̀ náà ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ọdún 2000, tí o tọpa rẹ̀ sí àkọọlẹ kàn ní inú ìwé ìròyìn The New York Times.[2][3] Látàrí ìtàn, ìdàgbàsókè àti bí ayé tí ń yìí, kò ì tí sí ìtumò kan ní pàtó tí wọ́n faramọ̀ fún orúkọ náà láti máa lò, èyí sí jẹ́ òun àríyànjiyàn.[4][5]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Facts About Nigerian Movies and History". Total Facts about Nigeria. Retrieved 22 October 2014. 
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named autogenerated6
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named autogenerated1
  4. "Nollywood Journal - Articles". nollywoodjournal.com. 2009-01-07. Archived from the original on 2014-01-31. Retrieved 2023-06-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "How Nollywood became the second largest film industry". British Council. 2015-11-06. Retrieved 2023-06-13.