Jules Bessan
Appearance
![](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/5/5d/Jules_Bessan_Rio2016.jpg/220px-Jules_Bessan_Rio2016.jpg)
Jules Yao Bessan (Ti a bi ni ọjọ kerinla oṣu kẹrin odun1979) je oluwe-odo ti orilẹ-ede Beninese . o se oju orilẹ-ede re ni idije 2016 Summer Olympics ni 50 mita elere o gbe ipo 77th pẹlu asiko 27.32 iseju aaya. Ko yanjun si ipele ti o kangun si asekagba.
Bessan si ni eniti Ami eye orilẹ-ede Benin ninu 50 mita elere ati 50 mita ọyan.