Johannes Hans Daniel Jensen
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti J. Hans D. Jensen)
Johannes Hans Daniel Jensen | |
---|---|
Ìbí | 25 Osu Kefa, 1907 Hamburg |
Aláìsí | 11 Osu Keji, 1973 Heidelberg |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | ara Jemani |
Pápá | fisiksi |
Ibi ẹ̀kọ́ | Yunifasiti ilu Hamburg |
Doctoral advisor | Wilhelm Lenz |
Doctoral students | Hans-Arwed Weidenmüller |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Ebun Nobel ninu Fisiksi (1963) |
Johannes Hans Daniel Jensen (June 25, 1907 ni Hamburg – February 11, 1973 ni Heidelberg) je ara Jemani to je onimo fisiksi inuatomu. Nigba Ogun Agbaye Keji, o sise lori ise okun inuatomu fun Jemani, to unje Agbo Uraniom, ninu ibi to ti se afikun pataki si ipinya awon isotopu uraniom. Leyin ti ogun pari, o sise bi ojogbon ni Yunifasiti ilu Heidelberg. O tun je ojogbon alejo ni Yunifasiti Wisconsin–Madison, the Institute for Advanced Study, Indiana University, ati the California Institute of Technology. Jensen pin Ebun Nobel ninu Fisiksi odun 1963 pelu Maria Göppert-Mayer fun aba won fun afijuwe igbaeyin inuatomu.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |