Jump to content

Gaston Browne

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Gaston Browne
Alákóso Àgbà ilẹ̀ Ántígúà àti Bàrbúdà 4k
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
13 June 2014
MonarchElizabeth II
Governor GeneralRodney Williams
AsíwájúBaldwin Spencer
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Gaston Alfonso Browne

9 Oṣù Kejì 1967 (1967-02-09) (ọmọ ọdún 57)
Villa/Point, Antigua and Barbuda
Ẹgbẹ́ olóṣèlúLabour Party
Alma materCity Banking College
University of Salamanca
Net worthUS$11.1 million (2014)[1]

Gaston Alfonso Browne (ọjọ́ìbí 9 Fẹ́ ebruary 1967) ni alákóso àgbà ilẹ̀ Antigua ati Barbuda. Òhun ni olórí orílẹ̀-èdè erékùṣù yìí láti ọdún 2014. Kó tó di olóṣèlú, ó jẹ́ oníṣẹ́ bánkì.


  1. "Prime Minister Gaston Browne the $30 Million Man". 12 June 2016. Retrieved 7 November 2018.