Elizabeth Adekogbe
ẹ̀yà | abo |
---|---|
country of citizenship | Nàìjíríà |
name in native language | Elisabeth Adekogbe |
orúkọ àfúnni | Elizabeth |
orúkọ ìdílé | Adékọ̀gbẹ́ |
ọjó ìbí | 1919 |
ìlú ìbí | Ìbàdàn |
ọjó ikú | 1968 |
spouse | Adékọ̀gbẹ́ |
native language | Èdè Yorùbá |
languages spoken, written or signed | gẹ̀ẹ́sì, Nigerian Pidgin |
writing language | gẹ̀ẹ́sì |
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀ | activist, olóṣèlú, civil service |
position held | tribal chief |
kẹ́ẹ̀kọ́ ní | Yaba College of Technology, St Agnes Catholic High School |
honorific prefix | tribal chief |
member of political party | Action Group |
ethnic group | Ìran Yorùbá |
eye color | brown |
hair color | Irun dúdú |
personal pronoun | L484 |
Oloye Elizabeth Adekoge(1919 - 1968)[1] jé olósèlú, ajafun ètó obinrin àti ajafun ominira Nàìjíríà nígbà ayé rè. Òun ní adari ajo women Council ti Nàìjirià. Ní odun 1959, ajo náà darapo pèlú Women's improvement league láti di egbé National Council of women societies,[2] egbé tí óún jà fitafita fún ètó obínrin ní Nàìjíríà.
Àárò ayé àti Èkó rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Adegoke sínú idile oba Ajaloorun ti Ijebu-Ife ní odun 1919. O kàwé ní St Agnes Catholic Training School àti ní College of Technology ti Yaba. Ó padà di osise ìjoba
Ipa rè nínú oselu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni odun 1952, Adekogbe àti awon obinrin merinla miran dá egbe women's movement kale ní ìlú Ibadan, ète àti erogba egbé náà ni fifi òpòlopò omobinrin sile ìwé, fifi awon obinrin sípò ase àti didin iye owo orí sisan kù.[3] O sisé pèlú àwon eniyan bi Funmilayo Ransome-Kuti láti ja fún ètó omobinrin.
Ìdílé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Elizabeth Adekogbe fé Alademerin Akija Adekogbe, ní odun 1946, àwon méjèjì kó lo sí Ibadan, ibè ni oko rè ti sise tita cocoa ní ilé-isé kan ní ibadan, tí Elizabeth sì jé adari ilé-ìwé primari Saint James ti ìlú Ibadan. Gegebi Oloye ní ilé Yoruba, Elizabeth lo je ipo Ìyálájé ti Ikija.[4]
Ikú rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Elizabeth Adegoke di ologbe ní odun 1968.[5]
Àwon ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Maitron". Maitron (in Èdè Faransé). Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Home". NCWSNigeria. 2021-03-15. Archived from the original on 2022-05-25. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Elizabeth Adekogbe and the Women’s Movement of Nigeria". The Republic. 2022-05-12. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Prabook". prabook.com. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Elizabeth Adekogbe" Check
|url=
value (help). Hyperleap. 1951-10-23. Retrieved 2022-05-28.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- CS1 Èdè Faransé-language sources (fr)
- Pages with URL errors
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from October 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1919
- Àwọn ọjọ́aláìsí ní 1968
- Àwọn olóṣèlú ará Nàìjíríà