Ali Nuhu
ẹ̀ka òwò | film industry, Ètò amóhùn máwòrán ti Nàíjíríà |
---|---|
ẹ̀yà | akọ |
country of citizenship | Nàìjíríà |
name in native language | Ali Nuhu Mohammed, Ali nuhu |
orúkọ àbísọ | Ali Nuhu Mohammed |
orúkọ àfúnni | Ali |
ọjó ìbí | 15 Oṣù Ẹ̀rẹ̀nà 1974 |
ìlú ìbí | Maiduguri |
native language | Èdè Haúsá, Waja |
languages spoken, written or signed | gẹ̀ẹ́sì, Èdè Haúsá, Èdè Lárúbáwá, Nigerian Pidgin |
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀ | òṣèré, film director, olóòtú eré, screenwriter |
ẹ̀kà iṣẹ́ | theater arts |
kẹ́ẹ̀kọ́ ní | Yunifásítì ìlú Jos |
academic degree | bachelor's degree, Bachelor of Arts |
residence | Kánò |
work period (start) | 1999 |
religion or worldview | Ìmàle |
eye color | black, brown |
hair color | Irun dúdú |
official website | http://www.alinuhu.net |
personal pronoun | L485 |
Ali Nuhu Mohammed (táabì ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, ọdún 1974) jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà àti olùdarí.[1]Ó má ń ṣe ère Haúsá àti ère Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn òní ròyìn má ń pè ní "king of kannywood" tàbí "sarki". Kannywood ni orúkọ ilé ìṣe fímù Hausa.[2] Nuhu ti kópa nínú àwọn ère Nollywood Àti Kannywood tí ó tó Ẹ̀dẹ́gbẹ́ta filmu. [3]
Early Life
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nuhu jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Maiduguri, Borno State ní Àríwá Ìwọ̀ Òrùn. Bàbá rẹ̀, Nuhu Poloma jẹ́ ọmọ Ìlú Balanga ni ìpínlẹ̀ Gombe àti Ìyá rẹ̀, Fátima Karderam Digema jẹ́ ọmọ ìjọba àgbègbè Bama ni ìpínlè Borno.[4]Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Jos àti Kano. Ó lọ sí Fáṣítì Jos, níbi tí ó ti gba Oyè ẹ̀kọ́ ní Arts.Ó ṣe Ẹ̀sìn orílè èdè ni Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ó padà lọ sí University of Southern California fun Ẹ̀kọ́ nínu ṣíṣe fíìmù àti àwọn ọ̀nà sinimá.[5]
Àkójọ̀pó Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ali Nuhu returns to school". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 13 October 2017.
- ↑ "An karrama Ali Nuhu da Adam Zango a London". bbc.com/hausa. BBC. Retrieved 13 October 2017.
- ↑ "Ali Nuhu, Adam Zango, others win awards in London". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 13 October 2017.
- ↑ https://www.voahausa.com/a/a-39-2005-08-06-voa1-91733284/1370189.html
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-10-10. Retrieved 2020-10-09.