Jump to content

Teodoro Obiang Nguema Mbasogo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Teodoro Obiang Nguema Mbasogo
Obiang in 2008
2nd President of Equatorial Guinea
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
3 Oṣù Kẹjọ 1979 (1979-08-03)
Alákóso ÀgbàCristino Seriche Bioko
Silvestre Siale Bileka
Ángel Serafín Seriche Dougan
Cándido Muatetema Rivas
Miguel Abia Biteo Boricó
Ricardo Mangue Obama Nfubea
Ignacio Milam Tang
Vicente Ehate Tomi
Francisco Pascual Obama Asue
Vice PresidentFlorencio Mayé Elá
Vicente Ehate Tomi
Teodoro Obiang Mangue
AsíwájúFrancisco Macías Nguema
Chairperson of the African Union
In office
Àdàkọ:Start and end dates
AsíwájúBingu wa Mutharika
Arọ́pòThomas Boni Yayi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kẹfà 1942 (1942-06-05) (ọmọ ọdún 82)
Acoacán, Spanish Guinea (now Equatorial Guinea)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Àdàkọ:Married
Àwọn ọmọTeodoro Obiang Mangue
RelativesArmengol Ondo (brother)

Teodoro Obiang Nguema Mbasogo (Pípè: [te.o.ˈðo.ɾo o.ˈβjãŋɡ ˈŋ.ɡe.ma m.ˈba.so.go]; ọjọ́ìbí 5 June 1942) ni olóṣèlú ará Guinea Ibialágedeméjì tó ti jẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Gínì Ibialágedeméjì láti ọdún 1979. Ó fi ipá gba ìjọba lọ́wọ́ arákùnrin bàbá rẹ̀, Francisco Macías Nguema, nínú ìfipágbàjọba ológun osù kẹjọ ọdún 1979, ó sì ti jẹ́ ààrẹ ibẹ̀ láoti ìgbà náà. Obiang dúró bíi Alága ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà láti 31 January 2011 dé 29 January 2012. Òhun ni ẹnìkejì tó jẹ́ olórí orílẹ̀-èdè tó pẹ́ jùlọ ní orí àga tí kìí ṣe ọba ní àgbáyé.[1] Ni Oṣu kọkanla ọdun 2021, Teodoro Obiang Nguema Mbasogo ni a yan ni apejọ apejọ ẹgbẹ rẹ gẹgẹbi oludije fun saa kẹfa ninu idibo 2023.