Jump to content

Shelly-Ann Fraser-Pryce

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Shelly-Ann Fraser-Pryce
Shelly-Ann Fraser, Moscow 2013
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdè Jamaica
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kejìlá 1986 (1986-12-27) (ọmọ ọdún 38)
Kingston, Jamaica
IbùgbéKingston, Jamaica
Height1.52 m (5 ft 0 in)[1]
Weight52 kg (115 lb; 8.2 st)
Sport
Erẹ́ìdárayáRunning
Event(s)100 m, 200 m
ClubMVP Track & Field Club

Shelly-Ann Fraser-Pryce, OD (ojoibi December 27, 1986)[2] je asare ori papa ara Jamaika. A bi ni Kingston, Jamaica, Fraser-Pryce gba ogo ninu awon Idije Olimpiki 2008, nigba to di obinrin elere idaraya oripapa akoko lati Caribbeanto gba eso wura ninu isare 100 m ni Olimpiki.[3] Ni 2012, o tun gba eso wura fun igba keji ninu isare 100m, eyi sodi obinrin keta to gba eso wura ninu isare 100m ni awon Olimpiki to telera.