Peter Rufai
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 24 Oṣù Kẹjọ 1963 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Lagos, Nigeria | ||
Ìga | 1.87 m (6 ft 2 in) | ||
Playing position | Goalkeeper | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1980–1984 | Stationery Stores | ||
1985 | Femo Scorpions | ||
1986–1987 | Dragons de l'Ouémé | ||
1987–1991 | Lokeren | ||
1991–1993 | Beveren | ||
1993–1994 | Go Ahead Eagles | 12 | (0) |
1994–1997 | Farense | 62 | (0) |
1997 | Hércules | 10 | (0) |
1997–1999 | Deportivo La Coruña | 9 | (0) |
1999–2000 | Gil Vicente | 1 | (0) |
National team | |||
1983–1998 | Nigeria | 65 | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Peter Rufai (ojoibi August 24, 1963 ni Eko) je amule fun agbaboolu agba omo ile Naijiria. O ba won kopa ninu ifesewonse to wa ye nilu Belgium, Netherlands ati ile Spain gege bi Amule Agba fun awon agbaboolu ile wa Super Eagle. O sise naa fun ogun odun gege bi ise oojo re. Bakan naa, o tun kopa ninu awon ifesewonse bii : idije agbaboolu ile Adulawo, idije ife ile-agbaye
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |