Nipsey Hussle
Nipsey Hussle | |
---|---|
Hussle in 2011 | |
Ọjọ́ìbí | Ermias Joseph Asghedom Oṣù Kẹjọ 15, 1985 Los Angeles, California, U.S. |
Aláìsí | March 31, 2019 Los Angeles, California, U.S. | (ọmọ ọdún 33)
Cause of death | Gunshot wounds |
Resting place | Forest Lawn Memorial Park, Hollywood Hills, California, U.S. |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–2019 |
Alábàálòpọ̀ | Lauren London (2013–2019; his death) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Musical career | |
Irú orin | Hip hop |
Labels | |
Associated acts | |
Ermias Joseph Asghedom (August 15, 1985 – March 31, 2019), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìtàgẹ́ rẹ̀ bíi Nipsey Hussle (ó sábà kọ ọ́ bíi Nipsey Hu$$le), jẹ́ olórin rap, alákitiyan, àti oníṣòwò ará Amẹ́ríkà.[1] Ó gbajúmọ̀ wá láti Los Angeles ní àrin àwọn ọdún 2000, Hussle dá fúnrara rẹ̀ gbé àwo-orin mixtape àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde, Slauson Boy Volume 1,[2] èyí ló fàá tí ó fi tọwọ́bọ̀wé àdéhùn pẹ̀lú Cinematic Music Group àti Epic Records.[3][4][5][6]
Hussle gbajúmọ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àwo-orin mixtape tó gbé jáde, nínú wọn ni Bullets Ain't Got No Name, The Marathon, The Marathon Continues, àti Crenshaw tí Jay-Z ra ogọ́rùún nínú wọn fún $100 fún ẹyọkan.[7] Lẹ́yìn ìfàsẹ́yìn, ó gbé àwo-orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde tó pè ní Victory Lap ní ọdún 2018,[8][9][10][11] wọ́n sì pè lórúkọ fún Ẹ̀bùn Grammy ọdún 2019. Lẹ́yìn tó di olóògbé, wọ́n fún ní Ẹ̀bùn Grammy méjì fún àwọn orin "Racks in the Middle" àti "Higher" (tó ṣe pẹ̀lú DJ Khalid) ní ibi àjọyọ̀ ẹ̀bùn Grammy ọdún 2020.[12]
Ó tún gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ òwò rẹ̀, Hussle dá ilé ìtajà Marathon Clothing sílẹ̀, pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Carless, olórí ilé-iṣẹ́ náà, Karen Civil àti pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Samiel Asghedom ní 2017,.[1][13] Ní ọjọ́ 31 oṣù kẹta ọdún 2019, wọ́n yìnbọn pa Hussle ní iwájú ilé-ìtajà rẹ̀ ní Los Angeles.[14] Eric Holder, ọkùnrin ọmọ-ọdún 29 tí òhun àti Hussle ti ní ìjiyàn ní àárọ̀ ọjọ́ náà, ní wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó yìnbọn pá.[15]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedLAT 2019-04-04
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:6
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedparle
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedWCNN1
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedXXLSept
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedauto4
- ↑ "Nipsey Hussle Breaks Down His $10,000 Album Transaction With Jay Z: Watch Now". MTV News. Archived from the original on September 17, 2014. Retrieved September 26, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Eric Skelton. "The First Week Numbers for Nipsey Hussle's 'Victory Lap' Are In". Complex. Archived from the original on March 7, 2018. Retrieved March 8, 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ McQuaid, Ian (February 16, 2018). "Nipsey Hussle: Victory Lap review – west coast rap at its finest". The Guardian. https://www.theguardian.com/music/2018/feb/16/nipsey-hussle-victory-lap-review-atlantic.
- ↑ Pearce, Sheldon (February 24, 2018). "Nipsey Hussle: Victory Lap Album Review". Pitchfork. Archived from the original on March 13, 2018. Retrieved March 13, 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Reviews for Victory Lap by Nipsey Hussle". Metacritic. Archived from the original on July 22, 2018. Retrieved September 21, 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "DJ Khaled Wins Best Rap/Sung Performance". The Recording Academy. January 26, 2020. Retrieved January 27, 2020.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:7
- ↑ "Rapper Nipsey Hussle killed in shooting outside his L.A. store" (in en). NBC News. March 31, 2019. https://www.nbcnews.com/news/crime-courts/man-killed-two-others-injured-outside-rapper-nipsey-hussle-s-n989371.
- ↑ Suspect in fatal shooting of rapper Nipsey Hussle captured in California, authorities say Archived April 4, 2019, at the Wayback Machine. The Washington Post, April 2, 2019]