George Lucas
Ìrísí
George Lucas | |
---|---|
Lucas at the 2009 Venice Film Festival | |
Ọjọ́ìbí | George Walton Lucas Jr. 14 Oṣù Kàrún 1944 Modesto, California, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Southern California |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 1965–present |
Net worth | US$5 billion (May 2020)[1] |
Olólùfẹ́ | Marcia Griffin (m. 1969; div. 1983) |
Àwọn ọmọ | 4, including Amanda Lucas, Katie Lucas |
George Walton Lucas Jr.[2] (bọjọ́ìbí May 14, 1944) ni aṣefílmù, ọlọ́rẹ, àoti oníṣòwò ará Amẹ́ríkà. Lucas gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tó ṣe àwọn fílmù bíi Star Wars àti Indiana Jones, àti olùdásílẹ̀ àwọn ilẹ́-iṣẹ́ Lucasfilm, LucasArts 'àti Industrial Light & Magic. Òhun ni alága Lucasfilm tẹ́lẹ̀ kí ó tó tàá fún The Walt Disney Company ní 2012.[3]
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "George Lucas". https://www.forbes.com/profile/george-lucas/. Retrieved May 7, 2020.
- ↑ White, Dana (2000). George Lucas. Lerner Publishing Group. p. 12. ISBN 0822549751. https://archive.org/details/georgelucas0000whit/page/12.
- ↑ "Disney Acquires Lucasfilm for $4.05 Billion – STAR WARS: Episode 7 in 2015!". broadwayworld.com.