Jump to content

Central African mangroves

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Central African mangroves ecoregion kún fún agbègbè ńlá tí o ní mangroveswamp ní orílè èdè Africa, tí ó wà ní coasts of West Africa pàápàá jù lọ ní orílẹ̀ èdè Nigeria.

A máa ń ṣe àwárí àwọn mangroves yí ní ẹnu odò Ọlọ́rà àti odò ńlá, ó sì kún fún igi tí ó ga tó 45m. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ igi bẹẹ wà ní orílẹ̀ èdè Nigeria, pàápàá jù lọ ní agbègbè Cameroon àti Equatorial Guinea/Gabonand patches ní Ghana, Democratic Republic of Congo àti northern Angola. Agbègbè tó tóbi jù ní ìgbèríko tí ó wà ní delta tí Niger Riveron the Gulf of Guinea, Èyí tó kù wa ní eastern side tí Cross River delta ní orílẹ̀ èdè Nigeria àti Cameroon, the Wouri estuary ní Cameroon àti Muni River estuary ní border tí Equatorial Guinea àti Gabon pẹlu the ẹnu odò Congo.