Air pollution in Delhi
Dídara afẹ́fẹ́ ni Delhi ní orílé èdè Índíà, gẹ́gẹ́ bí Ìwádìí láti ọwọ́ Àjọ Àgbáyé fún Ìlera |WHO] ti gbé àwọn ìlú lọ́na 1,650 yẹ́wó àti ṣe ìwádìí lórí awọn ilu ní agbaye lọnà 7,000 láti ọwọ́ Ilé-iṣẹ́ tí ó má nipa Ìlera ní orílé èdè America [2] ni ó burú jù ní eyíkéyí ilu ní àgbáyé. Ó tún kan àwọn agbègbè kan ní àyíká Delhi.[3][4] Ìdọ̀tí inú Afẹ́fẹ́ ní Íńdíà ní àfojú díwọ̀n iyé máa ń pa nǹkan bí mílíọ̀nù méjì ènìyàn lọ́dọọdún; Ó jẹ́ ààrùn apànìyàn kàrún tí ó tóbi jùlọ ní India. Orílè-èdè India ní òṣùwọn ikú tí ó ga jùlọ ní àgbáyé èyí tí àwọn àrùn atẹ́gùn, àwọn àrùn ikọ́ ife ati ààrùn inú eegun wá lára àwọn ààrùn, Gẹ́gẹ́ bí àjọ WHO náà tisọ. Ni Delhi, afẹ́fẹ́ tí kò dára tí ó jẹ́ pé bí ó báti wọ inú àgọ̀ ará máa ǹ bá nǹkan jẹ́ nínú ará èyí tí kòsí ní àtúnṣe máa ń bá ẹ̀dọ̀fóró jẹ́ tí bá to mílílọ̀nù méjì ẹdọfóró jẹ́, èyí tí ìlàjì sí jẹ́ àwọn ọmọdé.
Ní ọjọ́ 25 Oṣù kọkànlá ọdún 2019, Ilé Ẹjọ́ gíga tí ilé India ṣé àwọn àlàyé lórí ìdọ̀tí ní Delhi nínú ọ̀rọ̀ sisọ rẹ̀ “Delhi ti buru ju Naraka lọ (ọ̀run apáàdì lọ)".[5] Adájọ àgbà Justice Arun Kumar Mishra pé ì bá dáa tí wọ́n bá rí àwọn olóró èyí tí yóò yàrá pani jù ìdọ̀tí afẹ́fẹ́ lọ[6]
Lákòkò ìtìpa àgbáyé látàrí Àjàkáyẹ́ ààrùn COVID-19 èyí tí kò yọ Orílẹ̀-èdè India sílẹ, Omi tí àwọn odò Yamuna àti Ganges tí dára èyí sì tí mú ìlọsíwájú bá àwọn ilé-iṣẹ́ tí wá ní agbègbè ibẹ̀ látàrí títìpa ílú nítorí àjàkálẹ̀ ààrùn COVID-19.[7][8][9][10] Dídára afẹ́fẹ́ tún ti ní ìlọsíwájú pàtàkì ní àkókò títìpa.[11]Ní Orílẹ-èdè India ilé-iṣẹ́ ti ó mójútó Àwọn sáyẹ́nsì Àyè tí ṣe àtẹ̀jáde ìwé ìwádìí kan ní Oṣù Kẹwà ọdún 2018 tí ó sọ pé ó fẹ́rẹ̀ tó 41% sí àwọn ìtújàdè èefín ọkọ̀, 21.5% sí jẹ́ eruku nígbà tí 18% sì awọn ile-iṣẹ.[12] Olùdarí ilé iṣé fún ìmọ sáyẹnsì àti agbègbè tí fi ẹsùn kàn pé ilé iṣé Automotive ní orílé èdè India àti àwọn ọmọ ẹgbẹ Indian Automobile Manufacturers ń parowa “tí ó lòdì sí ìjábọ̀ náà” nítorí pé kò “rọrùn” sí ilé-iṣẹ́ tí ó ń ṣe Ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́Àṣìṣe ìtọ́kasí: Closing </ref>
missing for <ref>
tag
Àwọn ìdí àti ohun tí ó kó bá afẹ́fẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Èefín inú Ọkọ̀ Ayọ́kẹ́lẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára ohun tí ó ń kóbá afẹ́fẹ́.[13]Àwọn ohun ìmíìran ní sísun igi.[14][15] cow dung cake combustion,[16] iná dídá lórí àwọn Ilé tí à ń gbìn nǹkan sí, Èéfín inú Ẹ̀ro Diesel, àwọn eruku láti ibì ìkọlé, sisùn pàǹtí.[17] àti àwọn iṣẹ́ ilé-iṣẹ́ arúfin ní Delhi. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdọ̀tí tió jẹ́ èyí tí ó burú jùlọ láti Oṣù kọkànlá sí ìkinní, afẹ́fẹ́ Delhi ti pàdánù àwọn ìṣedédé afẹ́fẹ́ tí ó mọ́ nípasẹ̀ ààla jákèjádò fún ọdún púpọ. Ó jẹ́ àpòpọ̀ èéfín apanirun tí ó ń tú jáde láti àwọn ọkọ̀ ayọ̀kẹ́lẹ́ tí ó ń lọ bí mílíónù mẹ́sàn-án, ẹruku ìkọlé àti sísun ẹ̀gbin. Ní àwọn ọjọ́ tí ó burújú, ìtọ́ka benchmark Dídára afẹ́fẹ́, fí àlà tí ó wà láti òdo (dára) sí 500 (eewu), èyí tó kọjá 400.Àṣìṣe ìtọ́kasí: Closing
</ref>
missing for<ref>
tag.[18]
Àwọn ìṣẹlẹ pàtàkì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní oṣù Kejìlá ọdún 2017( ní ìgbà ere cricket tí àwọn ọmọ ẹgbẹ Sri Lankan ní Orílé èdè India ní ọdún 2017–18#Iyẹwo 3rd | baramu idanwo) èyí tí ó wáyé láàárín ọmọ ẹgbẹ́ Sri Lankan àti ọmọ Ẹgbẹ India tí ìlú Delhi, tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Sri Lankan bẹ̀rẹ̀ sí ní rí ìnira níbí mímí sókè àti sódò wọ̀n, èyí tí àwọn mìíràn bẹ síní bí nínú ilé ìgbọ̀sẹ̀ àti lórí páápá, àwọn mìíràn sí ní láti lo ìbomú títí wọ́n fi dá eré náà dúró..[19] Ní èrò Ààrẹ Indian Medical Association, ó pé eré náà ò bá ti má wáyé, àti pé àwọn ìgbìmò fún International Cricket yé kí wọ́n ní òfin lórí ìdọ̀tí.[20]
Èwo Àwọn wọ̀nyí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Delhi, Blanketed in Toxic Haze, "Has Become a Gas Chamber"". The New York Times. https://www.nytimes.com/2017/11/07/world/asia/delhi-pollution-gas-chamber.html.
- ↑ Koshy, Jacob (2022-08-17). "Delhi's PM2.5 levels worst in the world". The Hindu. https://www.thehindu.com/sci-tech/energy-and-environment/delhis-pm25-levels-worst-in-the-world/article65780144.ece?homepage=true.
- ↑ "Ambient (outdoor) air pollution in cities database 2014". who.int. WHO. 2014. Archived from the original on 28 March 2014. Retrieved 31 May 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Harris, Gardiner (14 February 2015). "Delhi Wakes Up to an Air Pollution Problem It Cannot Ignore". The New York Times. https://www.nytimes.com/2015/02/15/world/asia/delhi-wakes-up-to-an-air-pollution-problem-it-cannot-ignore.html.
- ↑ "'Delhi worse than hell': Supreme Court rebukes Centre, states on air pollution". Hindustan Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 November 2019. Retrieved 26 November 2019.
- ↑ ""Better To Get Explosives, Kill Everyone": Supreme Court On Delhi Pollution". NDTV.com. Retrieved 26 November 2019.
- ↑ "Lockdown makes Ganga water significantly cleaner". LiveMint. 4 April 2020. Retrieved 22 April 2020.
- ↑ Naqvi, Haider; Kumar, Sudhir (4 April 2020). "Lockdown does what decades of schemes couldn't: Clean Ganga". HT Digital Streams Ltd. Retrieved 22 April 2020.
- ↑ "India's coronavirus lockdown reveals fresh air, cleaner rivers". Living Media India Ltd. 22 April 2020. Retrieved 22 April 2020.
- ↑ Babu, Nikhil (14 April 2020). "Yamuna cleaner due to lockdown". The Hindu. Retrieved 22 April 2020.
- ↑ "The silver lining: air pollution dips amid the lockdown". https://www.indiatoday.in/india-today-insight/story/the-silver-lining-air-pollution-dips-amid-the-lockdown-1671422-2020-04-26.
- ↑ "Usual suspects: Vehicles, industrial emissions behind foul play". Times of India. https://timesofindia.indiatimes.com/city/delhi/usual-suspects-vehicles-industrial-emissions-behind-foul-play-all-year/articleshow/66228517.cms.
- ↑ Stewart, Gareth J.; Nelson, Beth S.; Drysdale, Will S.; Acton, W. Joe F.; Vaughan, Adam R.; Hopkins, James R.; Dunmore, Rachel E.; Hewitt, C. Nicholas et al. (2020-08-13). "Sources of non-methane hydrocarbons in surface air in Delhi, India" (in en). Faraday Discussions 226: 409–431. doi:10.1039/D0FD00087F. ISSN 1364-5498. PMID 33336656.
- ↑ Stewart, Gareth J.; Acton, W. Joe F.; Nelson, Beth S.; Vaughan, Adam R.; Hopkins, James R.; Arya, Rahul; Mondal, Arnab; Jangirh, Ritu et al. (2021-02-18). "Emissions of non-methane volatile organic compounds from combustion of domestic fuels in Delhi,India" (in English). Atmospheric Chemistry and Physics 21 (4): 2383–2406. Bibcode 2021ACP....21.2383S. doi:10.5194/acp-21-2383-2021. ISSN 1680-7316. https://acp.copernicus.org/articles/21/2383/2021/.
- ↑ Stewart, Gareth J.; Nelson, Beth S.; Acton, W. Joe F.; Vaughan, Adam R.; Farren, Naomi J.; Hopkins, James R.; Ward, Martyn W.; Swift, Stefan J. et al. (2021-02-18). "Emissions of intermediate-volatility and semi-volatile organic compounds from domestic fuels used in Delhi, India" (in English). Atmospheric Chemistry and Physics 21 (4): 2407–2426. Bibcode 2021ACP....21.2407S. doi:10.5194/acp-21-2407-2021. ISSN 1680-7316. https://acp.copernicus.org/articles/21/2407/2021/.
- ↑ Stewart, Gareth J.; Nelson, Beth S.; Acton, W. Joe F.; Vaughan, Adam R.; Hopkins, James R.; Yunus, Siti S. M.; Hewitt, C. Nicholas; Nemitz, Eiko et al. (2021-02-25). "Comprehensive organic emission profiles, secondary organic aerosol production potential, and OH reactivity of domestic fuel combustion in Delhi, India" (in en). Environmental Science: Atmospheres 1 (2): 104–117. doi:10.1039/D0EA00009D. ISSN 2634-3606.
- ↑ "A history of Delhi's air pollution: Can road rationing even the odds?". Hindustan Times. 4 January 2016. Retrieved 7 December 2017.
- ↑ Hartman, F. C.; LaMuraglia, G. M.; Tomozawa, Y.; Wolfenden, R. (1975-12-02). "The influence of pH on the interaction of inhibitors with triosephosphate isomerase and determination of the pKa of the active-site carboxyl group". Biochemistry 14 (24): 5274–5279. doi:10.1021/bi00695a007. ISSN 0006-2960. PMID 47. https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pubmed/47.
- ↑ Safi, Michael (3 December 2017). "Pollution stops play at Delhi Test match as bowlers struggle to breathe" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/world/2017/dec/03/pollution-stops-play-at-delhi-test-match-as-bowlers-struggle-to-breathe.
- ↑ Hartman, F. C.; LaMuraglia, G. M.; Tomozawa, Y.; Wolfenden, R. (1975-12-02). "The influence of pH on the interaction of inhibitors with triosephosphate isomerase and determination of the pKa of the active-site carboxyl group". Biochemistry 14 (24): 5274–5279. doi:10.1021/bi00695a007. ISSN 0006-2960. PMID 47. https://www.ncbi.nlm.nih.gov/pubmed/47.