Breadfruit: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
SolutionTomi (ọ̀rọ̀ | àfikún) Ṣ'èdá ojúewé pẹ̀lú "{{short description|Edible fruit-bearing tree in the family Moraceae}} {{other uses|List of plants known as breadfruit}} {{speciesbox|name=Breadfruit|image=Artocarpus altilis (fruit).jpg|image_caption=Breadfruit at Tortuguero, Costa Rica|genus=Artocarpus|species=altilis|authority=(Parkinson) Fosberg|synonyms=* ''Artocarpus altilis var. non-seminiferus'' <small>(Duss) Fournet</smal..." |
(Kò ní yàtọ̀)
|
Àtúnyẹ̀wò ní 11:28, 19 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2023
Breadfruit | |
---|---|
Breadfruit at Tortuguero, Costa Rica | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Ìbátan: | Artocarpus |
Irú: | A. altilis
|
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Artocarpus altilis | |
Synonyms | |
|
Breadfruit (Artocarpus altilis) jẹ́ ẹ̀yà igi olódòdó ti ìdílé mulberry àti jackfruit (Moraceae)[2][3] tí wọ́n gbàgbọ́ pé ó jẹ jáde láti ìran Artocarpus camansi, èyí tó wá láti New Guinea, ní Maluku Islands, àti Philippines. Ó kọ́kọ́ tàn ká síOceania ní Austronesian expansion. Lẹ́yìn náà ló tàn ká sí àwọn agbègbè mìíràn káàkiri ayé lásìkò ìjọba àwọn amúnisìn.[4][5] Àwọn ará ilẹ̀ Britain àti Faransé ṣe àmújáde ẹ̀yà aláìléso mìíràn ní òpin sẹ́ńtúrì kejìdínlógún. Lónìí, ó ń hù ní orílẹ̀-èdè àádọ́rùn-ún káàkiri apá Gúúsù àti Gúúsù-mọ-Ìlà-oòrùn ilẹ̀ Asia, Pacific Ocean, Caribbean, Central America àti Africa.[6] Orúkọ rẹ̀ jẹ jáde láti ara ìrísí èsò tí wọ́n sè lẹ́yìn tó bá pọ́n tán, èyí tó jọ búrẹ́dì tí wọ́n ṣe, tó sì dùn bí i potato.[6][7]
Wọ́n máa ń gbin igi náà ní Central America, northern South America, àti Caribbean.[5][6] Èso náà máa ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i oúnjẹ gigi ní àwọn ìlú mìíràn, wọ́n sì tún máa ń fi igi rẹ̀ kọ́ ilé àti ṣe ọkọ̀ ojú omi.
Breadfruit fara jọ Artocarpus camansi tó wà ní New Guinea, ní Maluku Islands, àti Artocarpus blancoi ti àwọn Philippines, (tipolo or antipolo) ti Philippines, àtiArtocarpus mariannensis (dugdug) ti àwọn Micronesia. Gbogbo wọn ni wọ́n ń pè ní "breadfruit". Bákan náà, ó fara jọ jackfruit.[8]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Artocarpus altilis (Parkinson ex F.A.Zorn) Fosberg". The Plant List. Retrieved 2016-01-12.
- ↑ "Jackfruit, Breadfruit, Osage Orange, Mulberry, Soursop, Sugar Apple, Cherimoya". palomar.edu. Palomar College. Archived from the original on 2021-04-11. Retrieved 2020-10-12. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Hepworth, Craig (2017-09-12). "Moraceae – The Mulberry Family". Florida Fruit Geek (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-12.
- ↑ Matisoo-Smith, Elizabeth A. (3 November 2015). "Tracking Austronesian expansion into the Pacific via the paper mulberry plant". Proceedings of the National Academy of Sciences 112 (44): 13432–13433. Bibcode 2015PNAS..11213432M. doi:10.1073/pnas.1518576112. PMC 4640783. PMID 26499243. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=4640783.
- ↑ 5.0 5.1 Morton, Julia F (1987). "Breadfruit". Fruits of Warm Climates. West Lafayette, Indiana: NewCROP, Center for New Crops and Plant Products, Department of Horticulture and Landscape Architecture, Purdue University. pp. 50–58. Archived from the original on 5 January 2015. Retrieved 17 January 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 6.0 6.1 6.2 "Breadfruit Species". ntbg.org. National Tropical Botanical Garden. 2017. Archived from the original on 8 November 2022. Retrieved 17 January 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Artocarpus altilis (breadfruit)". kew.org. Kew Gardens, Richmond, Surrey, UK: Board of Trustees of the Royal Botanic Gardens. 2017. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedDiane Ragone- Breadfruit