Tùnísíà (US /tˈnʒə/ two-NEE-zhə or UK /tjˈnɪziə/ tew-NIZ-iə; Lárúbáwá: تونسTūnis pronounced [ˈtuːnɪs]), lonibise bi Orile-ede Olómìnira ara Tùnísíà[note 1] (Lárúbáwá: الجمهورية التونسيةal-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah Àdàkọ:IPAc-ar), ni orile-ede apaariwajulo ni Áfríkà. O je orile-ede Maghreb kan, be si ni o ni bode mo Àlgéríà ni iwoorun, Libya ni guusuilaorun, ati Omiokun Mediterraneani si ariwa ati ilaorun. Aala re je 165,000 square kilometres (64,000 sq mi), pelu idiyele alabugbe to je egbegberun 10.4. Oruko re wa lati inu oruko oluilu re Tunis to budo si ariwa-ilaorun.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Tùnísíà
Tunisian Republic

الجمهورية التونسية
al-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah
Coat of arms ilẹ̀ Tùnísíà
Coat of arms
Motto: حرية، نظام، عدالة
"Ḥurriyyah, Niẓām, ‘Adālah"
"Liberty, Order, Justice"[1]
Orin ìyìn: "Humat al-Hima"
"Defenders of the Homeland"
Location of Tùnísíà
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Tunis
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaArabic[2]
Orúkọ aráàlúTunisian
ÌjọbaUnitary Presidential Republic [2]
• President
Kais Saied
Ahmed Hachani
Mehdi Jomaa
Independence
• from France
March 20, 1956
Ìtóbi
• Total
163,610 km2 (63,170 sq mi) (92nd)
• Omi (%)
5.0
Alábùgbé
• 2014 estimate
10,982,754[3] (79th)
• 2011 census
11,245,284[4]
• Ìdìmọ́ra
63/km2 (163.2/sq mi) (133rd (2005))
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$96.001 billion[5]
• Per capita
$9,025.067[5]
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$43.684 billion[5]
• Per capita
$4,106.747[5]
Gini (2000)39.8
medium
HDI (2010) 0.683[6]
Error: Invalid HDI value · 81st
OwónínáTunisian dinar (TND)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù216
ISO 3166 codeTN
Internet TLD.tn .تونس[7]

Tunisia je orile-ede to kerejulo to budo si eba oke Atlas. Guusu orile-ede na je kiki aginju Sahara, pelu eyi to to je kiki ile olora ati eti okun 1,300 kilometres (810 mi). Awon mejeji ko ipa pataki igba atijo, akoko pelu ilu Carthage awon Punic, leyin re bi igberiko ile Romu ni Africa, to gbajumo bi "apere onje /bread basket" ile Romu. Leyin re, Tunisia bo so wo awon Vandals ni orundun 5k LK, awon Byzantine ni orundun 6k, ati awon Arabu ni orundun 8k. Labe Ileobaluaye Ottomani, Tunisia je mimo bi "Iluoba Tunis/Regency of Tunis". O bo sowo ibiabo Fransi ni 1881. Leyin ominira ni 1956 orile-ede na di "Ileoba Tunisia" leyin ijoba Lamine Bey ati Iran-oba Husainid. Pelu ifilole Orile-ede Olominira ara Tunisia ni July 25, 1957, olori aseolorile-ede Habib Bourguiba di aare akoko.



  1. The long name of Tunisia in other languages used in the country is:
  1. "Article 4". Tunisia Constitution. 1957-07-25. Archived from the original on 2006-04-06. http://www.chambre-dep.tn/a_constit1.html. Retrieved 2009-12-23. 
  2. 2.0 2.1 "Article 1". Tunisia Constitution. 1957-07-25. Archived from the original on 2006-04-06. http://www.chambre-dep.tn/a_constit1.html. Retrieved 2011-04-02.  Translation by the University of Bern: Tunisia is a free State, independent and sovereign; its religion is the Islam, its language is Arabic, and its form is the Republic.
  3. "National Institute of Statistics-Tunisia". National Institute of Statistics-Tunisia. 12 September 2014. Archived from the original on 4 September 2015. Retrieved 12 September 2014. 
  4. "National Statistics Online". National Statistics Institute of Tunisia. July 2009. Retrieved 7 January 2009.  (Lárúbáwá)
  5. 5.0 5.1 5.2 5.3 "Tunisia". International Monetary Fund. Retrieved 2011-05-10. 
  6. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
  7. "Report on the Delegation of تونس.". Internet Corporation for Assigned Names and Numbers. 2010. Retrieved 8 November 2010.