Okoẹrú jẹ́ ìṣe ayé àtijọ́ tí àwọn ènìyàn kan máa ń ṣe káràkátà ọmọ ènìyàn mìíràn fún àwọn alágbára tàbí àwọn òyìnbó amúnisìn. Nínú okowò ẹrú, ọmọ ènìyàn ni ọjà tí wọ́n ń tà. Wọ́n máa ń kó àwọn ènìyàn tí wọ́n tà lẹ́rú lọ ṣiṣẹ́ oko àti àwọn ìṣe líle ni ìlú òyìnbó. Àwọn tí wọ́n bá kò lẹ́rú kì í ní òmìnira kankan bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n fi wọ́n ṣiṣé ní tipátipá.[1][2][3]

Àwòrán gbígbẹ́ tó ṣe àfihàn àwọn erú pẹ̀lú ìgbèkùn ní Ilẹ̀ọba Rómù, ní Smyrna, 200 CE.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe