Aisan Ara - Diseases of The Body - Ilera - Health

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 3

ÈNÌÀ- AWỌN ÀÌSÀN ARA

Level of readership General


by Fakinlede K

ENGLISH YORÙBÁ ENGLISH YORÙBÁ

AIDS Àìsàn Àìgbéṣẹ òkí-ara HIV Ọlọjẹ afàìgbéṣẹ òkí-ara


(illness caused by the (virus responsible for
inability of the immune inability of the immune
system to function) system to function)

Amnesia Ìgbàgbé Hookworm Jàgbàyà

Anaemia- Àìsàn àìlẹjẹtó Illness due to lack Àrùn ìwọsí


of hygiene

Anxiety Àìfọkànbàlẹ Infectious disease; Àrùn aranni


contagious disease;
Communicable
Disease

Jaundice Iba ponju-ponju

Asthmatic Ikọ efée Kwashiokor Kwaṣiọkọ


cough

Backache Ẹ̀hín ríro Leprosy Ẹ̀tẹ

Belly ache Inú rírun Malaria Ibà, Ibàá-gbóná

Body ache Ara ríro Measles Kitipi, èeyi

Boil Eéwo Meningitis Ibà-orí

Brain fever, Ibà orí Moist cough Ikọ dídẹ


meningitis

Nettle rash Inọrun


Cancer Jẹjẹrẹ Pneumonia Àrùn ẹdọforó

Canker, Ìbẹ Polio; poliomyelitis Àìsàn rọpárọsẹ; Àrùn


Stomatitis èsọ
̣ ò ̣pá-ẹhìn wíwú

Chicken pox Productive cough Ikọ fífẹ

Chigger Jìgá Pulmonary cough Ikọ àyà

Cholera Àrùn Onígbáméjì Rabies Àrùn dìgbòlugi

Coated Èfù Ringworm Ekùsá, làpálàpá,


tongue kúrùpá

Congenital Àrùn abínibí Scabies Èékú


disease

Cough Ikọ Scurvy Ekúru

Craw-craw Kuruno, Ìṣaka

Deficiency Àrùn àìdára ìjẹ àti Skin rash Eékú, Eéyi, ẹyún
disease imún

Dengue Ibà inú eegun Small pox Ṣọpọná, Ilẹẹgbóná,


(breakbone Òde, Ṣáṣá
fever)

Dental Ehín kíkẹ Stomach ache Inú rírun


caries**

Dental Gẹdẹgẹdẹ ehín Stomach ulcer Ọgbẹ-inú


plaque

Diabetes Àtọgbẹ Stroke Àrùn ègbà


̣

Diarrhea Ìgbẹ gbuuru Tooth cavity Akokoro

Head ache Orí fífọ Tuberculosis Jẹdọjẹdọ

Dry cough Ikọ gbígbẹ Typhoid fever Ibà jẹfunjẹfun


Dysentry Ìgbẹ ọrìn Typhus fever Ibà wórawóra

Elephantiasis Jàbùtẹ, Òkè Water borne diease Àrùn ẹgbin omi

Epidemic Àjàkálẹ-àrùn Whooping cough Ikọ líle ọmọdé

Epilepsy Wárápá Yaws, Frambesia Gbòdògì

Fever Ibà Yellow fever Ibà pupa

Furuncle Eéwo Hacking cough Ẹgbẹkọ

Diarrhea Àrunṣu Genetic disease Àrùn àfijogún; Àrùn


with ìdílé; Àrùn ìrandíran
stomach
ache

Gonorrhea Àtọsí Heart attack

Guineaworm Sòbìyà High blood pressure Ẹjẹ ríru

You might also like