Aseta Iyami
Aseta Iyami
Aseta Iyami
ODU:-OSA MEJI
FEEDING:
Female Hen
Baby Chiken
INCISIONS
16 ON HEAD
3 ON BACK
OFORE
A BA NI GBELE KO MO EKE
ESU ODARA NI AWO AGBODE JIFA
ORISA LO DERU SEYIN ABUKE DAINDAIN
ADIFA FUN EPO ROGUN OMO ALARA
ABU FUN TIRAN MON WON LORUN AWO OKE IJERO
ADIFA FUN EWO TI SOMO IKOFA AGBONNIREGUN
AYE SEBI ERE BI ERE WON PA EPO ROGUN OMO ALARA
WON PA TIRAN MON WON LORUN AWO OKE IJERO
O WA KU EWO TI SOMO IKOFA AGBONNIREGUN
ENIKAN KI PA EWO
ENIKAN KIJE EWO
AJE O NI BURU KOJE ERUN
OSO O NI JE ERU
ATELO
ATEBO
KI SE YANGI OJU ONA NI NKANKAN
OSA MEJI BAMI SA GBOGBO ABURU ARA MI DANU
ENGLISH