Itadogun Reflexão
Itadogun Reflexão
Itadogun Reflexão
(TRADUÇÃO)
filho de Osun
Oyeku-Ogbe
Àjíkáwon mó lé iná
Àjí ká won mól òjò òwúrò
Díá fún Ìká
Ti yóó ká Ìrosùn mólé
Nítorí akokoro orí eran gbígbe
Kùtùkùtù n’Ìká ti ká Ìrosùn mólé
Títí alé fi lé kokooko
Òfún rànyìnrànyìn
Díá fún Ákàtànpó
Ti nrán Efón omo rè re’gbò
Wón níkó rúbo
Ó fe’bo saló
Olúigbó wá mú omo rè s’óhùn-ún
Njé àlo la rí
A ò mà mà ri àbò mó o
Gbogbo won wá di ráseráse o
Òfún rànyìnrànyìn
Consultou Ifá para a atiradeira
Quando atirava flechas com seus filhos na floresta
Foi aconselhada a fazer Ebó, ela não aceitou
O senhor da floresta pôs seus filhos na atiradeira
Espere, eu só preciso que vocês sejam atirados
Nenhum de vocês regressará
Todos se perderam
Pèlépèlé lojúmó n mó
Pèlépèlé lalélé n lé
Pèlépèlé là n pàmúkùùrù u pèlé
Bá ò bá fi pèlépèlé pàmúkùùrù u pèlé
A ro’ni títí lo dé ponpolo itan
Díá fún Oníwàyó
Ti nlo soko Òròrò-Ewà
Wón ní kó sákáalè, ebo ní síse
Ó f’ebo saló
Kí nlo so Oníwàyó dahun?
Òròrò-Ewà
Ló so Oníwàyò dahun?
Òròrò-Ewà
Kí nlo wá pa Oníwàyò gbangba?
Ahun Òròrò-Ewà
Ló pa Oníwàyò gbangba?
Ahun Òròrò-Ewà