Adurà Ibeji
Adurà Ibeji
Adurà Ibeji
Igbà Órìsà
Órìsà Ibéjì
Dakùn dabó, ma jékì a rì Ikù Omodé,
Ma jékì a rì Ikù agbà,
Enitì ó bì, máà jékì ó sokùn,
Máà jékì a kù Ikù airotélé,
Fun mi lowó latì sé nkan gbógbó,
Iwó ti só alakisà di alasó, jowó só akisà mi di asó,
Iwó to ti essè mejé ji bé silé alakisà, jowó bé silé mi,
Órìsà Ibéjì, pelé ó,
Ejiré àra isokùn,
Jowó só mi di oloró.
(Orixá eu te saúdo)
(Orixá Ibeji)
(Não permita que haja a morte de crianças)
(Não permita que haja a morte de adultos)
(Quem tem para não chorar)
(Não deixe acontecer a morte imprevista)
(Me dê dinheiro para minhas necessidades)
(Você que torna o pobre rico, me torne rico)
(Você que entrou na casa do pobre, peço entre na minha)
(Orixá Ibéjì eu te saúdo)
(Ejirê de Issokun)
(Peço, me torne próspero).