Iwe Isegun Awon
Iwe Isegun Awon
Iwe Isegun Awon
ITUWO AIYE
OGUN IKORIRA
OGUN IJAKULE
OWU ALANTAKUN
ALAKALA
ISENARE:-
Ti aba dele aobo epo ara atare yen danu, aoni jeki omo atare yen bo Sonu oo aofi ogbon bo epo yen nio,
aowa ko gbogbo omo atare yen aoko si oju olo tabi inu odo, aogun papo mo ewe Ajeobale yen ti yio
kunna daada, aowa po mo ose eyi toba wuwa, boya lux tabi Ghana tabi eyikeyi
Aowa ko ose yen sinu Ike funfun. Aoma fi we ni alale kia to sun. Odaju gidi.. Tio bafe kosise fun oo
daadaa koko share si opolopo group, kio si fi comment re se adura fun mi kio to dawo le...
ENITI ISE YII BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MON BIO SEFESE KIO MESSAGE MI LORI
WHATSAPP ((09027426795)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE
FUN IBEERE TIONI ITUMON ATI FUN IRANLOWO ONAABAYO SI GBOGBO ISORO AYERE CALL OR
WHATSAPP OLAIFA AWAYEWASERERE TIOBA NIGBAGBO ((09027426795))