12 Odù de Òtúrúpòn
12 Odù de Òtúrúpòn
12 Odù de Òtúrúpòn
Òtúrúpòn Méjì A
Ifá pé kì eléyìun ó rúbo. Yóó jèé ènìyàn pàtàkì.
Òtúrúpòn Méjì A
Ifá le pide a esta persona que realice sacrificio. Él se volvería una persona importante en
la vida.
Òtúrúpòn Méjì B
Ifá pé ire fún eléyìun. Ebo kó le baà se àseyorí ni kó rú. Ifá pé enìkan ó mùú eléyìun dé
ibì kan. Wón ó mò ó sí ajé, sí omo sùgbón kó rúbo.
Òmúni dé ìlú
Kò tó adélùúmò
A díá fún Onígbàjámò
Omo a pónbe lórí awo
Wón ní ó sá káalè ó jàre
Ebo ní ó se
Ó sì gbébo nbè
Ó rúbo
Njé rírú ebo níi gbéni
Àìrú kìí gbèèyàn
Kèé pé o
Ònà è jìn
E wáá ba ni ní jèbútú ire
Jèbútú ire làá bá ni lésè Oba Òrìsà
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Méjì B
Ifá desea bien a esta persona. Él debe realizar sacrificio de éxito. Alguien lo tomaría en
alguna parte. Allí, las personas lo reconocerían para la riqueza y los niños pero él debe
ofrecer sacrificio.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ogbè A
Ifá pé òun pé ire eléyìun. Òpòlopò omo ni eléyìun ó bìí, sùgbón ebo ayé ni kó rú fún
àwon omo òhún.
Òtúrúpòn Ogbè A
Ifá le desea la fortuna buena de niños a esta persona. Él tendría muchos niños pero él
debe ofrecer sacrificio para los enemigos terrenales que pueden estar contra los niños.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ogbè B
Ifá pé kí eléyìun ó rúbo kó sì móo bo egbé. Ifá pé ká rú èkuru, ká sì rúbo asían tí won ò
mo kókó è, tí won ò sì rójútùú è. Àrùn tí ó móo lo tí ó tùún móo sérí. Ifá póun ò níí jé kí
wón ó rí i.
Òtúrúpongbè pongbá
Porangandan
Kúmóla ponmo lègbè kunkun
A díá fún Adígbónránnkú
Èyí tí ó fikú òrun sèdóró
Wón ní kó rúbo
Kó sì móo bo egbéé rè
Adígbónránnkú rúbo
Sugbon agbára rè ò ká gbogbo eboo rè
Bó bá ti kú
Ní tún n dáá jí
Ngbà ó jé pé ìwòn tí apáa rè ká ló rú
N ní wá n jó ní wá n yò
Ní n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òtúrúpongbè pongbá
Porangandan
Kúmóla ponmo lègbè kunkun
A díá fún Adígbónránnkú
Èyí tí ó fikú òrun sèdóró
Adígbónránnkú
Mo se bóo kú ni?
Ngbà wo lo fòrun sàrèbò?
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ogbè B
Ifá le piden a esta persona que realice el sacrificio a sus compañeros celestiales. Él debe
ofrecer Èkuru. Ifá también quiere que él sacrifique contra una cierta enfermedad que
ellos no saben su fuente y cura, la enfermedad que sería recurrente. Ifá dice que él no les
permitiría verlo.
Òtúrúpongbè pongbá
Ponranngandan
Kúmólá ponmo lègbè kunkun
La adivinación lanzada para Adígbónránnkú
El que usaría la muerte para causar el pánico
Le pidieron que realizara sacrificio
Y también ofrecer sacrificio a sus compañeros celestiales
Adígbónránnkú realizó el sacrificio
Él sólo sacrificó dentro de su capacidad
Cuando él se desmayó
Él se resucitaría
Desde que él ofreció sólo el tamaño pequeño de sacrificio que él podría permitírselo
Todavía él estaba bailando y estaba regocijando
Él estaba alabando sus Babaláwos
Sus Babaláwos estaban alabando Ifá
Él dijo que era exactamente como su Babaláwos dijeron
Òtúrúpongbè pongbá
Porangandan
Kúmólá ponmo lègbè kunkun
Adivinación lanzada para Adígbónránnkú
El que usaría la muerte para causar el pánico
Adígbónránnkú
Yo había pensado que usted se murió
¿Cuándo usted convirtió la experiencia de muerte a una jornada de retorno?
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òyèkú A
Ifá póun ó bàá eléyìun ségun. Ifá pé bí ón bá gbé ogun ká eléyìun mó ilé, ipá ò níí ká a;
sùgbón kó rúbo. Rere ní gbogbo nnkan tí eléyìun dá Ifá sí sùgbón kó tún rúbo òmìmì
kan; lójú kan náà ni kó lòó ra Àkùko adìe kí wón ó móo wáá lé Àkùko òhún kiri wón ó
fi mú u, lójú kan náà ni kí wón ó ti pa á gbogbo ohun tíí je Ajogún pátá ní ó lo.
Omí sí omí n lo
Àgbàlagbà omi ni ò wèyìn wò
A díá fún Òrúnmìlà pèlú Òlódùmarè
Níjó tí Ajogún dí won mólé pin pin pin
Òrúnmìlà àti Òlódùmarè ni ón gbé jogún ká mólé
Òlódùmarè àti Òrúnmìlà ló sì mó ìdí ayé
Òlódùmarè bá ké sí Òrúnmìlà
‘Ajogún ló dé yìí’!
Òrúnmìlà ní á á ségun
Wón bá rúbo
Wón mú Àkùko adìe
Wón fi bo òkè ìpòríi won
Gbogbo Ajogún bá sé pátá
Òrúnmìlà bá kèjàsì
Ó léekú ò omo Àgbonnìrègún gbogbo Babaláwo
Wón ní Hin
Oomí sí omí n lo àgbàkagbà omi ni ò wèyìn wò o
Hin
A díá fún Òrúnmìlà pèlú Òlódùmarè níjó Ajogún ká won mólé
Hin
Ó ní wón ti mókòòkó lékú lo ò o ò o
Enìkan ò mògbà tIfá fí mókòkò lékú ló ò
Enìkan ò mògbà tIfá fí mókòkò lékú ló ò ò ò
Enìkan ò mògbà tIfá fí mókòkò lékú ló o ò o
Enìkan ò mògbà tIfá fí mókòkò lékú ló o o o
Òtúrúpòn Òyèkú A
Ifá dicen que él ayudaría que esta persona prevaleciera. Todas las personas belicosas
contra él nunca lo superarían, pero él debe realizar sacrificio. Ifá dice que está bien
sobre lo que él está consultando pero él también debe hacer su sacrificio para cubrir una
prueba ácida (mordaz) que viene. El sitio dónde este Ifá se lanza, él debe ir y debe
comprar un gallo, soltarlo para correr; ellos deben seguirlo entonces, deben capturarlo y
entonces deben matarlo en el sitio de Ifá. Todas las cosas llamadas Ajogún irían.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òyèkú B
Àwon kan n dábàá láàrin araa won pèlú ení ó dá Ifá yìí. Ifá pé àbá ení ó dá Ifá yìí ní í se.
Apá eléyìun ó kàá nnkan.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òyèkú A
Ifá dice que algunas personas están sugiriendo (sugestionar, haciendo pensar) ideas
dentro de ellos. Ifá dice que es la propuesta de esta persona que demostraría verdad
(derecho, bueno, apropiado). Ifá dice que él le permitiría a esta persona superar la vida.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìwòrì A
Ifá pé kí eléyìun ó mú enu è le lee le kó lè baà ségun elénìní è. Ifá pé kó sì móo sòótó;
torí enu tí bá fí n fohùn náà ni kó móo fi ségun. Nnkan tó bá dáa ni ko móo so jáde lénu.
Ifá loun ò níí jé kí ogun ó mu eléyìun.
Ponlawi
Pònlàwì
A día fún Ògún
Èyí tí n be láàrin Òsììrì
Tí n be láàrin otá sángílítí
Ebo n wón ní ó se
Wón ní kí Ògún o rúbo
Wón sí n gbógun tìí
Wón ní Ìbon ní ó ba ségun
Won ò se méjì mó
Ìbon ni ón gbé kò wón lójú
Ayé ye Ògún
Ìbón bá Ògún ségun
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Ponlawi
Pònlàwì
A día fún Ògún
Èyí tí n be láàrin Òsììrì
Tí n be láàrin otá sángílítí
Ebo n wón ní ó se
Ògún gbébo nbè
Ó rúbo
Ponlawi
Pònlàwì
Enu tí ìbón fí n fohùn
Ní fí n ségun
Mo mòmò rúbo Òtúrúpònlàwì
Òtúrúpòn Ìwòrì A
Ifá desea bien a esta persona. Él se manda para ser persistente en sus discursos
(lenguaje, habla, conversación) para que él superara sus detractores. Él también debe
decir la verdad porque está con la misma boca que él usaría para superar. Él debe hacer
declaraciones buenas. Ifá dice que él no permitirá la guerra para arrestarlo.
Ponlawi
Pònlàwì
Adivinación lanzada para Ògún
Que estaba en medio de es los enemigos jurados
Él estaba en medio de los enemigos
Le pidieron que realizara sacrificio
Ellos le pidieron a Ògún que realizara sacrificio
Cualquiera que emprendió las guerras contra el Arma (pistola, fusil, cañón) es belicoso
contra Ògún
Ellos dijeron que es el Arma que ganaría para Ògún
Ellos no hicieron nada más
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìwòrì B
Ifá pé wón n se ìlèkùn ir emó eléyìun. Ifè pé kó rúbo kí ìlèkùn olà náà ó sí. Odidi ìlèkùn
eran ò je kan lebo è; kí wón ó ha á sí ebo òhún. Àwon Babaláwo ó je ìyókù lérù. Ojú
ònàà rè ó là.
Etibonke; Etibonke
Èèmò ni mò ó,
Èèmò kín lojú ò tiè rí rí
A díá fún Ewúré
Tí n lo rèé filé sòfé je
Etibonke; Etibonke
Èèmò ni mò ó,
Èèmò kín lójú ò tiè rí rí
A díá fún Èèyàn tí ó gbara è kàle lówó Ewúré
Èèyàn ni Ewúré n kó ní nnkan
Gbogo nnkan àwon ni wòn n kó jeé tán lo
Bóo làwon ti wáá lè se?
Wón níwo Èèyàn rúbo
Ké e ségun eni tí n ko yin ní nnkan
Wón ní wón ó kan ìlèkùn tí à n pè ní Eran ò je
Wón bá kan ìlèkùn
Sùgbon Ewúré ló kó rúbo
Tí n filéé sòfé je
BÉwúré bá ti dé ibè
Ewúré ó bàá móo wò sùùn
Àti wolé ó di nnkan
Yóó sì móo wo n tí ó je lóòókán
Ngbà ó bá pé títí
Àrúfín ebo tí Ewúré rú
Won ò tún níí mo eni tí ó tùún sílèkùn sílè
Sùgbón Èèyàn sá gbara è kalè
Ifá pé eboo ká gbara eni kalè ni ká rú
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìwòrì B
Ifá dice que la puerta de fortuna está estando (siendo) cerrada en esta persona. Ifá le
pide que ofrezca una media puerta como sacrificio para la puerta abrir. La media puerta
se desecharía en el sacrificio. Los Babaláwo tomarían el restante como un regalo libre.
Nadie estaría de pie en su camino.
Etibonke; Etibonke
Es una aberración entristeciendo que uno debe saber
¿Incluso una aberración, qué es que el ojo nunca había visto antes?
Adivinación lanzada para la Cabra
Que iba a devorar las comidas de la casa gratuitamente
Etibonke; Etibonke
Es una aberración entristeciendo que uno debe saber
¿Incluso una aberración, es qué el ojo había visto nunca antes?
Adivinación lanzada para Hombre que se salvaría del alboroto de la Cabra
Es la cabra que estaba robando las cosas del Hombre
'Todas mis cosas se pierden'
'Que yo haré ahora'? el Hombre se preguntó
Ellos le dijeron al Hombre que realizara el sacrificio
'Usted superaría a la persona que roba sus cosas
Ellos le pidieron al hombre que hiciera una puerta llamada 'Eran ò je'
El hombre hizo la puerta
Pero era la Cabra primero realizó el sacrificio
Y había estado devorando comidas de la casa gratuitamente
Una vez la Cabra llega a la entrada
La cabra miraría en la casa con el pesar
Entrar se vuelve una tarea
Él vería qué comer mientras estrella (marcado con asterisco) a él
Después de un período prolongado
La eficacia del sacrificio realizada por la Cabra
Nadie sabría quién abriría el pestillo de la media puerta
Pero el Hombre se libró del alboroto de la Cabra
Ifá dice que es el sacrificio de libertad que esta persona debe realizar
El hombre ganó y empezó a bailar y regocijar
Ellos estaban alabando sus Babaláwos
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òdí A
Ifá pé ire fún eléyìun, ayé ó ye é; sùgbón kó rúbo ajé. Eléyìun ó kòó ilé nlá kan lára odò.
Àwon Méjì nIfá n báá wí. Tí àwon méjèèjì bá jo rúbo, wón ó jo níyì láyé ni.
Òtúrúpòndí eyé bà
Òtúrúpòndí eyé fò
A díá fún on lóde Eégún
A bù fún on lóde Èyò
Níjóo wón n fojú sògbérè ire gbogbo
Wón ní àwon ará òde Ègùn àti àwon ará òde Èyò ó rúbo
Ifá pé wón ó jo gbayì láyé
Owó sì ni wón n wá lode Eégún
Omo ní n je wón níyà lode Èyò
Ayé ye wón
Gbogbo ire tí wón n wá ni wón rí
Ayé ye wón tán ni wón n jó ni wón n yò
Wón n yin àwon Aláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Wón ní béè làwon Babaláwo tàwón wí
Òtúrúpòndí eyé bà
Òtúrúpòndí eyé fò
A díá fún on lóde Eégún
A bù fún on lóde Èyò
Níjóo wón n fojú sògbérè ire gbogbo
Wón ní wón ó sá káalè wón ó jàre
Ebo ni wón ó se
Wón wáá gbébo nbè
Wón rúbo
Ègùn n lówó o
Eyó n bímo
Awo rere lÒtúrúpòndí
Òtúrúpòn Òdí A
Ifá desea bien a esta persona. Ifá dice que él construiría una casa al lado de un río. Ifá le
pide que realice sacrificio para la riqueza. Ifá está refiriéndose a dos personas. Ellos
podrían ser conocidos en todo el mundo.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òdí B
Ifá pé kí eni táa dá odù yìí fún ó se dáadáa sí ìyá tó bí I lómo; Kí nnkan tí ò dára ó mó
wàá selè.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Nítorí ìyáa rè
E mó sàì bá mi jé ò
Gbogbo ènìyàn
E mó sàì bá mi jé ò
N ló wáá di mósà nlé ayé
Òtúrúpòn Òdí B
Ifá le aconseja a esta persona que ame bien a su madre; tal que las cosas malas, no
tendrían atascar (parar, ahogar) su éxito. Su madre lo ama a él tanto.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìrosùn A
Ifá pé òun pé ire. Eléyìun ó jìyà jìyà, sùgbón yóó sì jòrò. Ará ó rò ó, nnkan ò níí dàrú
mó o lówó. Ojúu rè ó rìíre. Sùúrù púpò ni ká se.
Òtúrúpòn Ìrosùn A
Ifá dice que él desea bien a esta persona. Él sufriría mucho pero se bendeciría
finalmente. Su vida sería agradable y sus cosas no se pondrían estropear.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìrosùn B
Ifá pé òun pé ire fún ení ó dá odù yìí. Ki eléyìun ó mo òwò tí ó bàá móo se dáadaa. Òwò
òwú kìí se isé eléyìun, Ifá pé kó rúbo kí isé tí n se kó leeré nnú sì le jèrè è. Ebo ni kó rú.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìrosùn B
Ifá desea bien a esta persona. Ifá quiere que tenga cuidado en el tipo de comercio o
trabajo que él haría. No le aconsejan fuertemente comercio en algodón y debe ofrecer el
sacrificio para el éxito y rentabilidad de comercio.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òwónrín A
Ifá pé ká rúbo ààrè; òun ò níí jé á ri àrùn. Ká sì rúbo ìdajì ara ràbí odò abè. Èèyàn
takuntakun ni eléyìun; kí nnkan tíí múùyàn lódò abé ó mó wàá so eléyìun di òle ni kó
rúbo sí
Òtúrúpòn Òwónrín A
Ifá habla bien. Esta persona debe realizar el sacrificio para anticipar una cierta (cierto,
seguro) enfermedad. El tipo de enfermedad afecta el medio cuerpo, o las áreas genitales.
Él es que una persona enérgica pero la enfermedad de los órganos genitales pueden
volverlo a una persona perezosa.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òwónrín B
Ifá pé àwon méta kan ni wón ó mowó araa won láti òkèèrè sí òkèèrè. Àwon métèèta ó
móo rí araa won télè; won ò wáá níí ri araa won mó. Ifá pé kí eléyìun ó mó jà o. Kí wón
ó sì mó ro èrò tí ò dáa sí ara won. Wón ó rìí araa won, ìmòràn tí ón sì n gbà lórí eléyìun
ò níí se.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Èsín lé won
Wón bó sódò Òkò
Òkò tún kó won lérú
Wón tún bó sóde Òyó
Àwon ará òde Òyó dè wón towó tesè pin pìn pin
Àwon jagun jagun ó gbúròó araa won
Ojó yí lu ojó
Osù yí lu osù
Oba Òyó wáá wò ó njó kan pé
Àwon tóun tiè ní kí wón wáá bóun jagun
Won ò wa gbó isé òun ni?
Òun ò rí Òkò
Òun ò rí Èsín
Òyó bá gbé onísé dìde lòó bá Èsín
Pé kó fojú kan òun
Ngbà ó dé
Obá ní ‘Hówù’?
‘Gbogbo ogun tí àwón ó jo jà’
‘Òun ò sì ri yín mó’?
Èsín ní ‘Kínni’
Ojó táwon fi Ogun sí un
Njo náà ni ogún ká òun mólé
‘Bóo le ti wáá se’?
Wón làwon lé won ni
Ó tún bó sílèe Lìkì
Òun náà tún kéjó ó rò
Òyó ní béè náà ni Abóóda dódò òun
Lòun náà kéjó
Ló rò
‘Àsé tÈsín bá Èsín ni’
‘TÒkò bá Òkó’
‘Àsé tAbóóda náà ló bá Abóóda’
‘Ní ò jé á ríraa wa’
N won wá n jó ní wá n yò
Won n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Wón ní béè làwon Babaláwo tàwón wí
Òtúrúpòn wón nIfá
Omo Awo ò ríkìi re
A kùkòòkan sààsà lénu àwon àgbàlagbà
A díá fún Èsín tíí somoo wón lóde Ìda
A díá fún Òkò
Omoo won nílèe Lìkì
A díá fún Abóóda
Tíí somoo won lóde Òyó
TÈsín lo bÈsìín o
Ni ò jé á ríraa wa
TÒkò ló bá Òkò
Ni ò jé á ríraa wa
TAbóóda náà ló bAbóóda
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ni ò jé á ríraa wa
Òtúrúpòn Òwónrín B
Ifá dice hay tres personas quienes se conocerían íntimamente. Ellos se localizan en las
ciudades diferentes y habían estado viendo frecuentemente antes, cuál no es de nuevo
ahora posible. Ifá les pide que sean cautos en la asunción (suposición) encima de la
razón para la pérdida de contacto. Ellos se encontrarían pronto.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òbàrà A
Ifá pé kí eléyìun ó rú abèbè méjì fún Èsù. Ise enu ni kí eléyìun ó móo se; isé tí ó móo
sòrò lénu nisée rè. Ifá pé òun ò níí jé ó rí àdàgúnlè esè; esè tí ó móo gbé e kiri tí ó fi
móo sòrò. Ifá pé kí eléyìun ó rúbo, wón ó móo ké e.
Òtúrúpòn Òbàrà A
Ifá le piden a esta persona realizar sacrificio a dos manos (entrega, dar) entusiastas
(admirador, ventilar, soplar) a Èsù. Su trabajo se relaciona a su boca; Ifá no le permitiría
desarrollar una enfermedad de la pierna; la misma pierna que lo tomaría alrededor para
defenderse su comida. Él se cuidaría.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òbàrà B
Ifá pé ònà èyìn Òdí kán n be tí eléyìun móoó lo tàbí tí ón féé mú u lo. Tí eníkan bá n mú
u lo; kó lo, sùgbón tó bá je pé òun ló féé mú èèyàn kan lo sí èyìn odi, kò gbodò dan wò.
Won ò níí mò ó.
Pondara
Pòndàrà
A díá fún Itú
Èyí tí n pon Òdàrà lo silè Ifè
Itú ló mònà Ifè
Òdàrà ò mònà
Itú sì n sòwò lo sIfè
N lo àlobò ní gbogbo ìgbà
N jèrè
Èsù bá bi Í leeré
‘Ìwo Itú’
‘Nbí tóòó móo lo un’
‘Mú òun lo’
‘Tóo bá mú òun lo’
‘Ó dún mó òun’
Òdàrà gbó enà
Ó mo bí ón tíí sètùtù
Ó sì mebo
Itú bá ní ó kálo
Ngbàa wón dóhùún
Àwón bá rù ú
Wón sò ó
Bóo ni nnkan àwon ti lè dáa?
Òdàrà sì n be nítòsí
Ó ní Itú lebo
Ni nnkaan yìn fi lè dáa
Wón bá mú Itú
Wón bá fi Itú rúbo
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Pondara
Pòndàrà
A díá fún Itú
Èyí tí n pon Òdàrà lo silè Ifè
Pondara
Pòndàrà
Ègbà àì sebo
Ègbà àì tù èèrù
Itú ló pon Òdàrà dálè Ifè
Ló bá já sórí ikú
Òtúrúpòn Òbàrà B
Ifá dice que hay un cierto lugar en el extranjero que alguien está planeando llevar
(tomar) esta persona. Él debe seguir a este amigo. Pero si es él que esta de viaje a este
lugar él no debe llevar (tomar) a nadie junto con él. Él no se reconocería allí.
Pondara
Pondara
Adivinación lanzada para Itú
El que estaba de atrás asegurado Òdàrà a Ilé Ifè,
Es Itú que supo el camino a Ilé Ifè
Òdàrà lo imploró entonces
'Usted Itú
'Esta ruta de comercio suya'
'Por favor lléveme'
'Si usted puede ayudarme'
'Yo estaré muy contento ' Òdàrà pidio a Itú
Odara es sin embargo conocedor en los idiomas torcidos (trenzados) (trabalenguas)
Él también sabe tanto sobre los rituales
Y ofreciendo sacrificio
Itú le pidió que viniera
Cuando ellos llegaron a la ciudad de Ilé Ifè
Ellos, en Ilé Ifè estaban rumiando en sus problemas domésticos
Ellos decidieron consultar con Ifá
'Cómo habría nuestras cosas anotar un hecho bueno' era la pregunta que ellos estaban
haciéndole a Ifá
Òdàrà estaba cerca
¡En el idioma torcido, Òdàrà dijo 'Itú es el objeto de sacrificio'!!!
'Ésa es la única manera para que sus cosas serían buenas'
Eso era cómo ellos prendieron a Itú
Y la usó como sacrificio
Pondara
Pondara
Adivinación lanzada para Itú
Que era Òdàrà fuerte en su regreso a la ciudad Ifè
Pondara
Pondara
El mal de no realizar el sacrificio
El problema de no dar los regalos libres
Itú dio correazos a Òdàrà a la ciudad de Ifè, Y resultó causa (fuera, exterior) de muerte
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òkànràn A
Ifá yìí bèère sùúrù púpò. A lè ti móo se nnkankan fún òpòlopò èèyàn tí ó sì móo dára;
sùgbón bó bá ti dí ibi tiwa, kò níí gún. Ifá pé ká rúbo ká sì fara balè, láìpé, gbogbo è ní ó
dayò.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òun ò rójútùú è
Èmú ní lóòóto ni
Ó ní tìe náà ó dáa
Èmú níré tó o bá gbá mú
Kò níí bó mó o lówó
Èmú ní ‘sóo mó mí’?
‘Sóo sì mo Àrògìdìgbà’
Àrìnjó Olúfè lóun ò mò ó
Ó ní kálo òdò Àrògìdìgbà
Kóun náà ó fún o ládùúà
Wón bá loòdò Àrò
Àrògìdìgbà ní gbogbo ire táwon bá fun o
‘Gbogbo è ní ó rò mó o’
Àrògìdìgbà ní só mo Àdí omo Elébu?
Ó lóun ò mò ó
Ó ní kálo sódò Àdí
Ngbàa wón dódò Àdí
Àdí ní láí
Òròò re ò tún já díjú mó
Àdí ní ‘njé ó mo Osùn’?
Osùn tíí solóríi gbogbo Eleye lójúde ìsálayé?
Ó lóun ò mò ó
Wón dódò Osùn
Osùn ní Háà
Gbogob ire ní ó sùn ó bò
Osùn ní só mó Olómìnrìnyíhùn
Tí è é pahùn Obàrìsàá dà
Tó jé pé gbogbo ihun tí ón bá wí fún un
Tí ò fi níí yè
Ó lóun ò mò ó
Ó ní kálo òdò Olómìnrìnyíhùn
Olómìnrìnyíhùn náà ko hà
Gbogbo ihun tí ón toro fún o lónìí
‘Gbogbo è ní ó rìí béè’
Ó ni àwon ayé ni ò férààn re tó
Àwon ayé náà ó wàá férààn re
N ní wá n jó n ni n yò
Ní n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Kòkòrò jewé jewé
Kòkòrò jèlú jèlú
Kòkòrò tó jèlú jàre èlú
Ìwòn lewé tí n be lókoó dáraá mo
A díá fún Àrìnjó Olúfè
Níjó tí n sehun gbogbo tókan ò lójú
Ó wáá rìn títí
Ó lóun n lo sóde òrun
Ó bÉmùú Oníbodè Olòrun
Èmú níre tó bá mú ò níí bó mó
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òkànràn A
Este verso de Ifá nos exige ser muy dócil. Esta persona puede haber estado logrando los
hechos (hazañas, proezas) para las personas, pero las cosas demostrarían muy difíciles
para él. Ifá nos implora que seamos pacientes: Y que antes de largo, todos se volverían a
la alegría.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òkànràn B
Ifá pé èmí eléyìun ó gùn láyé.
Ikú polósí
Awo Omodé
Ikú pàwon àgbààgbà sànkò sànkò
Awo Olùkòsì
A díá fún Àgbàníkòró
Èyí tí n lo rèé won kúnlè ikin lódun n dídá
Òun ò kú báyìí?
Ó bá mú Ejì kún eéta
Wón ní kó rúbo
Wón ní yó pèé pèé pé láyé
Wón ní yóó gbòó
Yóó sì tó
Wón ní kó mó sì jáyà
Àgbàníkòró bá rúbo
Ayé bá ye é
Ó pé láyé
Ipáa rè ká nnkan
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Ikú polósí
Awo Omodé
Ikú pàwon àgbààgbà sànkò sànkò
Awo Olùkòsì
A díá fún Àgbàníkòró
Èyí tí n lo rèé won kúnlè ikin lódun n dídá
Èmí di Èrìyánntefé o
N ò níí bá won kú ní kékeré
Èrú pé; Èrú pé lomodéé tayò
N ó pèé pèé pé
N ó gbòó gbòó gbó
N ó là làà là
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òkànràn B
Ifá dice que esta persona tendría la vida larga.
Ikú polósí
El Babaláwo de Omodé
Ikú pàwon àgbààgbà sànko sànkò
El Babaláwo de Olùkòsì
Adivinación lanzada para Àgbàníkòró
El que habría con ellos dar con la rodilla anualmente para lanzar adivinación usando
Ikin
¿Yo no me moriría? Él preguntó
Entonces combinamos dos cauris con tres
Ellos le dijeron que realizara el sacrificio
Ellos le dijeron que él se mantendría en la tierra mucho tiempo
Él sería muy viejo
Y también es firme a la vejez
'Pero no ejerce el miedo' ellos aseguraron
Àgbàníkórò realizó el sacrificio entonces
La vida lo agradó entonces
Él vivió mucho tiempo
Él pudo superar muchos obstáculos
Él dijo que era exactamente como sus Babaláwos habían dicho
Ikú polósí
El Babaláwo de Omosé
Ikú pàwon àgbààgbà sànkò sànkò
El Babaláwo de Olùkòsì
Adivinación lanzada para Àgbàníkòró
El que habría con ellos dar con la rodilla anualmente para lanzar adivinación usando
Ikin
Yo me vuelvo Èrùyánntefé
Yo no me moriré joven con ellos
Èrú pé; es el estilo que los jovenzuelos usan jugando el juego de ayò
Yo viviría mucho tiempo
Yo me envejecería
Yo me haría extensivamente rico
Èrú pá; es el estilo que los jovenzuelos usan en juego de ayò.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ògúndá A
Ifá pé kí eléyìun ó rúbo ayò. Láti ìbèrè niree rè ó ti bá a wá, sùgbón kó fún òkè ìpòrí è
ní Ewúré kan. Ifá pé kí won ó mó wí ewúré òhún, kí wón ó hó awo è kí wón ó sì fì
kànlù.
Jógede
Gbàgede
A díá fún Òòsààlà Òsèèrèmògbò
Níjóó tí n tòrun bò wálé ayé
Ebo n wón ní ó se
Jógede
Gbàgede
A díá fún Òkànlénú Irúnmolè
Níjóó wón n tòrun bò wálé ayé
Wón ní kí gbogboo wón ó rú eran méjì méjì lo
Òòsà lórí òun ò gbó
Òòsà bá rúbo
Wón ho awo eran òhún
Wón e kànlù
Ngbàa wón dé ilé ayé
Àwon Òòsà ró kù ò rílù jó
Wón bá dé àjo nbi wón ó ti jó
Enii wón n sápéé fún
Eni rí n korin lásán
Òòsà bá yo lóòókán
Ó ní Jógede
Gbàgede
A díá fún Òòsààlà Òsèèrèmògbò
Níjóó wón n tòrun bò wálé ayé
Jógede
Gbàgede
Ifá jé n gbayì ntèmi
Bí Sàngó ti tó un
Kò rílù jó
Jógede
Gbàgede
Bí Ògún ti tó un
Kò rílù jó
Jógede
Gbàgede
Òòsà ní n be léyìn
Tí n jíjóo re
Wón bá fìlù bé e
Ògún ní háà
Òun náà bí nbi ìlú
Ògún bá lòó kan Àgèrè
Sàngó lòó kan bàtá
Gbogbo wón bá kànlù
Gbogbo ihun tí ò bá nílú nnú
Kò leè sehun rere kan tó dáa
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ògúndá A
Ifá le pide a esta persona que realice sacrificio para felicidad. Su fortuna había estado
con el derecho de su nacimiento. Él debe darle una cabra a Ifá. La piel de la cabra no
debe estar quemada pero debe quitarse y debe usar para hacer un tambor.
Jógede
Gbàgede
Adivinación lanzada para Òòsààlá Òsèèrèmògbò
En el día que él estaba viniendo del cielo a la tierra
Le pidieron que realizara el sacrificio
Jógede
Gbàgede
Adivinación lanzada para las Deidades incontables
En el día que ellos estaban viniendo del cielo a la tierra
Ellos pidieron a todos ellos sacrificar dos cabras
Òòsà dijo que él no puede atreverse a las consecuencias
Òòsà realizó el sacrificio
Ellos despellejaron la cabra
Y usaron la piel para hacer un tambor
Cuando ellos llegaron a la tierra
Las otras Deidades no podrían encontrar un tambor para bailar
Ellos llegaron a dónde ellos congregarían para bailar
Algunos estaban para aplaudirse
Algunos sólo estaban formando los ritmos con su boca
Òòsà, mira desde lejos, cantando
Jógede
Gbàgede
Adivinación lanzada para Òòsààlá Òsèèrèmògbò
En el día él estaba viniendo del cielo a la tierra
Jógede
Gbàgede
Ifá me permitió ser renombrado solo
Tan grande como Sàngó es
Él no tiene ningún único golpe de tambor para bailar
Jógede
Gbàgede
Tan poderoso como Ògún es
Él no tiene ningún único golpe de tambor para bailar
Jógede
Gbàgede
Es Òòsà que viene de atrás
Que está bailando sus merecidos golpes de tambor para bailar
Jógede
Gbágede
Es òòsà que viene de atrás
Que está bailando sus golpes de tambor merecidos
Ellos tamborilearon ruidosamente
En la desesperación, Ògún exclamó
'Yo también tengo una idea de un tipo de tambor
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ògún
Fue a hacer el tambor de Àgèrè
Sàngó hizo Sátà
Todos ellos empezaron la fabricación de tipos diferentes de tambores
Todas las celebraciones desprovistas de golpes de tambor
No connotaría una función buena
Òtúrúpòn Ògúndá B
Ifá pé òun pé ire fún eléyìun, kó rúbo è kó pé. Kò gbodò sí láàrin àwon eni rí ó ba ebí
jé. Ifá pé kó sì rúbo kí wón ó mó gba nnkan baba è lówó è.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ògúndá B
Esta persona no debe comprometer los actos capaces de estropear los lazos familiares.
Ifá le pide que realice el sacrificio que para que una cierta propiedad tenida por su padre
no se apoderan de él.
Òtúrúpòn gúnda
Òtúrúpòn gede
Ò dámo lògèdèngbé
Gégédédé ni wóón tàpá elégédé
Adivinación lanzada para la Hiena
Que fue pedido realizar el sacrificio
Tal que él ascendería al trono de dirección de sus padres
Òtúrúpòn gúnda
Òtúrúpòn gede
Él lucha con su ganando antagonista con una caída del alfiler
Gégédédé ni wóón tàpá elégédé
Adivinación lanzada para el Leopardo
Que fue pedido realizar sacrificio
Tal que él ascendería al trono de dirección de sus padres
La Hiena siempre había sido superior
Él fue el uno cuyos antepasados siempre se había entronizado como los líderes
El leopardo siempre había sido el diputado (delegado)
La Hiena se puso lenta sin embargo en la acción
Él no ofreció sacrificio a tiempo
El leopardo sacrificó diez hojas rápidamente
Él sacrificó 'aso-fínfín'
Él que ofreció su sacrificio totalmente desde los días antiguos
Está con el efecto inmediato que la elevación de la persona tendría lugar
No hay ninguna otra manera redonda hasta la fecha
Una vez que el sacrificio se observa por completo y la eficacia de las ofrendas
demostrada
Él sabría inmediatamente
El sacrificio demostró eficacia entonces para el Leopardo
La Hiena que había sido el líder anterior fue quitada
Ògìdán se volvió el nuevo líder en cambio
Después de que el Leopardo se había establecido
La Hiena se despertó de su letargo
Todos los animales llegaron a su campo de representación
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òsá A
Ayé eléyìun ó dáa; ó là fún; Ire ilé, ajé àtire òpòlopò èèyàn. Kó múrá sí nnkan tí n se
lówó kó forí è tì síbìkan. Ifá pé Òòsà ni kí eléyìun ó lòó bó. Òpòlopò igbín lebo è sí
Òòsà.
Òtúrúpòn Òsá A
Ifá dice que estaría bien con esta persona. Todas las buenas fortunas se destaparían para
él, riqueza, casas y el descanso, Ifá dice que él ha estado haciendo algo de importancia.
Él debe continuar y debe asegurarse para sacar una conclusión buena. Ifá le insta
(insiste) ir y ofrecer muchos caracoles a Òòsà.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òsá B
Ifá pé ebo ni kí eléyìun ó rú. Ifá pé òun ò níí jé ó kú. Àyà n já a nbi ó wà; Òpòlopò otí ni
kó wá fún àwon èèyàn tí n be lágbègbè.
Òtòlò je
Òtòlò mu
Òtòlò fesè lésèe tàárò kùtùkùtù
A díá fún Yéwándé
Tó fodún méta wà tí ò gbuuru
Òtòlò je
Òtòlò mu
Òtòlò fesè lésèe tàárò kùtùkùtù
Yéwándé tó fodún méta wà tí ò gbuuru
Ló fosù méfà lée wo tÒgbààrà
Àtògbuuru àtògbààrà
Àwon ló díá fún on nIlòógbòo tàbú
Omo a wúwo lówó ikú gbinringbinrin
Wón ní kí wón ó rúbo
Àwon ará Ìlógbòo tàbú bá rúbo
Ayé ye wón
Èmíi wón gùn
Àwon náà?
Layé ye báyìí?
N ní won wá n jó ní wón wá n yò
Won n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Wón ní béè làwon Babaláwo tàwón wí
Òtòlò je
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtòlò mu
Òtòlò fesè lésèe tàárò kùtùkùtù
A díá fún Yéwándé
Tó fodún méta wà tí ò gbuuru
Ló fosù méfà lée wo tÒgbààrà
Àtògbuuru àtògbààrà
Àwon ló díá fún on nIlòógbòo tàbú
Omo a wúwo lówó ikú gbinringbinrin
Ikú gbé mi ó tì mí
Mo jomi mo wúwo
Mo yò gbuuru
Mo yò gbààrà
Àrùn gbé mi ó tì mí
Mo jomi mo wúwo
Mo yò gbuuru
Mo yò gbààrà
Òfó gbé mi ó tì mí
Mo jomi mo wúwo
Mo yò gbuuru
Mo yò gbààrà
Gbogbo Ajogún gbé mi ó tì mí
Mo jomi mo wúwo
Mo yò gbuuru
Mo yò gbààrà
Òtúrúpòn Òsá B
Ifá le pide a esta persona que realice sacrificio. Él está ejerciendo miedo en su morada
presente; él debe comprar vino para las personas en su morada. Descansaría del miedo.
Òtòlò come
Òtòlò bebe
Òtòlò agrega pasos a los pasos tomados primero en la vida
Adivinación lanzada para Yéwándé
Que había estado casado durante tres años sin tener un niño
Òtòlò come
Òtòlò bebe
Òtòlò agrega pasos a los pasos tomados primero en la vida
Adivinación lanzada para Yéwándé
Que había estado casado años sin tener un niño
También existe durante seis meses sin tener alguna fortuna buena
Ògbuuru junto con Ògbààrà
Son unos que lanzaron adivinación para ellos en Ìlógbòo tàbú
El niño de A wúwo lówó ikú gbinringbinrin
Les pidieron que realizaran sacrificio
Las personas de Ìlógbòo Tàbú observaron el sacrificio
La vida los agradó así
Ellos tenían la vida larga
Sorprendido, ellos exclamaron
Ellos empezaron a bailar y regocijar entonces
Ellos estaban alabando su Babaláwos
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìká A
Ifá pé ire lòpòlopò. Bí eléyìun bá n lo sírìn àjò, kò gbodò pé kó tóó sérí wálé torí àwon
oore rè gba kóun gaan ó wà nlé kó tóó dáa. Èèyàn tíí móo lo tí móo bò ni eléyìun, ó lé
móo lo sùgbón kò gbodò pé tí ó fì padà. Ifá pé ire ibùjókòó fún un.
Òtúrú pònká
Òtúrú pònko
Pònko pònko bí efón sogi
A díá fún Ajá
Tí n fomi ojú sògbérè omo
Wón ní yóó bímo lòpòlopò ebo ní ó se
Òún le bímo láyé yìí
Tí gbogbo èèyàn ó mo òun báyìí?
Wón ní omoo ré pàpòjù ìwo Ajá
Ajá bá rúbo
Ajá bá n bímo
Ní bá n bí méje
Ní n bí méfà
Ajá bímo ó pò
Omo ò ní mòmó mó
Lajá wá n jó ní n yò
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òtúrú pònká
Òtúrú pònko
Pònko pònko bí efón sogi
A díá fún Ajá
Tí n fomi ojú sògbérè omo
Wón ní yóó bímo lòpòlopò
Ebo omo ni kó wáá se
Ajá gbébo nbè
Ó rúbo
Àkó ajá ì í pé lóde
Wàràjà
E jé á relé rèé gbómo
Wààràjà
Òtúrúpòn Ìká A
Ifá dice que estaría bien con esta persona. Ifá le pide que no diga que se queda
demasiado largo en un tropiezo de viaje porque el éxito de todas sus fortunas exigiría su
presencia física. Él es una persona que viaja a menudo; él todavía podría viajar pero
debe regresar pronto. Ifá le desea la fortuna buena de residencia permanente.
Òtúrú pònká
Òtúrú pònko
Pònko pònko bí efón sogi
Adivinación del lanzamiento para el Perro
En el día él estaba llorando debido a los niños
Ellos dijeron al Perro realizar sacrificio
¿Tendría yo niños en la tierra? El Perro había preguntado
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìká B
Ifá pé eléyìun ó mo ebo kó sì móo sòótó. Ení bá n sòótó níí gbádùn ilé ayé
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìká B
Ifá le pide a su persona que diga siempre la verdad. La verdad le haría disfrutar la vida.
Él también debe realizar el sacrificio de este Odù
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òtúá A
Ifá pé kí eléyìn ó rúbo. Kó tójú obì, àgbébò adìe àti owó kó wáá fi ra gbogbo ara è
pátápátá lógànjó òru. Kí wón ó wáá pa adìe tó fi rara è lóru òhún kan náà; tó bá di ojó
keji, kó sè e fún àwon èèyàn je. Kó kó obì àti owó fún àwon tí ón móo bo egbé, kí wón
ó bá a bo egbèrun. Ará ó rò ó, ayé è ó dáa.
Òtúrúpòn Òtúá A
Ifá le pide a esta persona que consiga un kola, gallina, y dinero; él debe acostumbrarlo
todos a frotar su cuerpo en lo muerto de la noche. La gallina es matada el mismo medio
de la noche y se cocinada para las personas para comer el próximo día. El kola y dinero
deben dinero ser dados a los devoto de Egbé para ofrecer como sacrificio para él. La
vida sería después más fácil para él.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Àrò
Òtúrúpòn Òtúá B
Àlejò kán n bò wáá bá eléyìn; àmì èèyàn ni. Ifá pé ká kìlò fún obìnrin eni lórí àlejò
òhún. Kí obìnrin eni ó mó lèé àlejò òhún lo. Bo bá jé obìnrin ni wón dá Ifá yìí fún, kí
wón ó kìlò fún un kó móo se dáadáa sí oko è.
E kú onílé
E ò nIfáá dá
Wón féé dáfá
Owó ni ò sí lówóó won
A díá fún Òrúnmìlà
Níjó ti n sawoó re ibi àtòkèdókè
Ó bá ya ilé omo ìkófáa rè
Ngbà ó dé ilé è
Ó bá Obìnrin rè tí n gún ògì
‘Nbo ha ni gbédègbeyò òún lo’?
Ó ló ti lo bíí tíí lo nùu
Dípòo kó tiè sodóó lè
Kó wá oko è lo
Kò sodóó lè
Kò mò pé àmì èèyàn ló wá oko òun wá
Ó bá júwe ònà ibi tí oko è lo fún Òrúnmìlà
Kò tún dáwó ògì tí n gún dúró
Òrúnmìlà bá korí síbè
BÒrúnmìlà ti dé ojú ònà
Omo ìkófáa è bá yo
Wón koraa won lójú ònà
Ní n pé e móo wolè baba
E móo wolè
Òrúnmìlà ní ta n lobìin tí n be nta un
Ó lóbìin òun ni
Òrúnmìlà láyè è ti bàjé
Ká móo tayàyà.
Òtúrúpòn Òtúá B
Ifá dice que un visitante de marcada (notable) identidad está viniendo a visitar a esta
persona. Ifá le pide que advierta a su esposa sobre el visitante inminente. El visitante es
Ifá y tal que la mujer no habría de ahuyentarlo. Si esta persona es una mujer, ella debe
ser de conducta buena a su marido.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìretè A
Awo gidi ni eléyìun; Ifá pé ká rúbo, wón n gbé òrò kan bò wáá bá a; ajogun ni òrò náà,
sùgbón yóó ségun. Kó bèèrè lójú opón, nnkan baba è tí àwon òtá ti féé gbà, won ò ní
leè gbà á. Ifá pé yóó ségun, nnkan náà ó sì di tiè.
Òtúrúpòon tètè
Awo tòótó tòótó
Awo tòdodo tòdodo
A díá fún Àwòko
Èyí tíí somo olórò níjù
Baba Àwòko ló ni Igbó
Àwon kán bá ní àwón ó gba igbó lówó è
Àwòkó ní kò séwu
Àwòkó bá rúbo
Wón ò le gba igbóo baba Àwòko mó
Ayé ye é
Ó ní Òtúrúpòon tètè
Awo tòótó tòótó
Awo tòdodo tòdodo
A díá fún Àwòko
Èyí tíí somo olórò níjù
Ebo n wón ní ó se
Kí wón ó mó gba igbó ilée baba è
Àwòko gbébo nbè
Ó rúbo
Rírú ebo èèrù àtùkèsù
E wáá bá ni ní màrínrín ire
Màrínrín ire làá bá ni lésè oba Òrìsà
Wón ò leè gba igbó ilée babaa rè mó
Òtúrúpòn Ìretè A
Ifá dice que esta persona es un sacerdote bueno pero él debe realizar el sacrificio porque
ellos están trayendo un Ajogún para encontrárselo; pero él ganaría. Los enemigos no
podrían apoderarse de una herencia de sus antepasados que ellos están a punto de robar.
Ifá le pide que inquiera (consultar, averiguar) de la propiedad particular, como este
pueda robarse sin su conocimiento. Él prevalecería.
Òtúrúpòon tètè
El sacerdote realmente verídico
El sacerdote realmente derecho (ergido, vertical)
Adivinación lanzada para Àwòko
El niño del hombre rico en los bosques profundos
Es el padre de Àwòko que poseyó los bosques
Algunas personas se confabularon para apoderarse de él entonces
No hay ningún problema, dijo Àwòko
Àwòko realizó el sacrificio
Ellos no podrían tomar el arbusto de nuevo de Àwòko
La vida lo agradó así
Él dijo Òtúrúpòon tètè
El sacerdote realmente verídico
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Ìretè B
Ifá pé kí eléyìun ó rúbo kó mó móo se àsedànù.
Òtúrúpòon tètè
Awo tòótó tòótó
Awo tòdodo tòdodo
A díá fún Sùgùdù
Tí ón ní ó rúbo kó mó baà lekó àlenù lásán lásán
Sùgùdù ò rúbo
Bí ón bá sì gbé Sùgùdù
Tí ón se okó è tonto
Béè báà ní ó wà lo
Kò níí kákò
Kò níí loolè
Wón ní alálenù leléyìí
Sùgùdù lóun ò mò pé bí ó ti rí nìí
Ì bá se pé ebó sée dá padà séyìn
Àyìn éyìn ní n yin àwon Babaláwo è
Àwon Babaláwo è n yin Ifá
Ó ní béè làwon Babaláwo tòún wí
Òtúrúpòon tètè
Awo tòótó tòótó
Awo tòdodo tòdodo
A díá fún Sùgùdù
Tí ón ní ó rúbo
Kó mó baà lekó àlenù lásán lásán
Sùgùdù ìwo lòó seun
Ìwo lòó sèèyàn
O wá n lekó àlenù lásáán lo
O mòmò gbébo
Béè lóo tu èèrù Sùgùdù
O wá n lekó àlwnù lásán lásán
Òtúrúpòn Ìretè B
Ifá le pide a esta persona que sacrifique contra los actos destructivos (malgastador,
prodigos, manirrotos).
Òtúrúpòon tètè
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òsé A
Àwon méta nIfá n báá wí nínú odù mímó yìí; àwon métèèta ó láyé. Ifá pé nnkaan babaa
won kàn n be nlè; won ò gbodò jé kí nnkan òhún ó sonù. Kí won ó tójú àdáyébá
Òtúrúpònsé ni ò légán
Òkìtì mo gbeère jù
Abiamó bùrìn bùrìn
Abiamó korin hèé ò omoo re
A díá fún Onílé Owó
A díá fún Oníkáa Wùsì
A díá fún Ato Òfòrí
Tíí somo ìkéyìin won lénje lénje
Wón kí àwon métèèta ó rúbo
Wón láyé ó ye wón
Onílé Owó rúbo
Oníkáa Wùsì náà rúbo
Ato Òfòrí náà rúbo
Àwon métèètá bá là
Ayé ye wón
Ni won wá n jó ní wón n yò
Won n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Wón ní béè làwon Babaláwo tàwón wí
Òtúrúpònsé ni ò légán
Òkìtì mo gbeère jù
Abiamó bùrìn bùrìn
Abiamó korin hèé ò omoo re
A díá fún Onílé Owó
A díá fún Oníkáa Wùsì
A díá fún Ato Òfòrí
Tíí somo ìkéyìin won lénje lénje
Wón kí àwon métèèta ó sá káalè ó jàre
Ebo ni wón ó se
Onílé Owó gbébo
Ó rúbo
Oníkáa Wùsì gbébó
Ó rúbo
Ato Òfòrí gbébo nbè
Ó rúbo
Onílé owó relé è
Ó lo rèé lówó
Oníkáa Wùsì relée rè
Ó lo rèé Wùsì
Ato Òfòrí ló relé ebora tó lo rèé là
Òtúrúpòn Òsé A
Ifá está refiriéndose a un grupo de tres en este verso sagrado. Los tres serían sumamente
ricos. Hay una riqueza que pertenece a su antepasado; no debe permitirse perderse.
Ellos deben esforzarse por proteger la herencia ancestral.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òsé B
Eléyìun jé onísòwò tíí tajà tí àwon èèyàn ó móo fún òun gaangan lówó. Ifá pé kó rúbo kí
enìkejì è lórun ó mó wàá ra ojà lówó è láyé. Aso funfun lebo è.
Òrúpa jégédé
Awo ebá ònà
A díá fún Ato
Níjó tí n sòwò rojà Èjìgbòmekùn
N lo rèé pónko
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Wón ní kó rúbo
Ato n pón èko lója Èjìgbòmekùn
Ó wo aso àdìre sára
Òkìkí kàn
Gbogbo èèyàn ní n ra èko lówó Ato
Èkejì Ato lórun bá ní òún ó loòdo Ato
Òún ó lòó ra èko lówó è
Wón sì ti so fún èèkejì rè pé aso àdìre ni Ató ró
Ató bá sùn
Oorun rè ò já geere
Wón ní kí Ató ó fi aso araa rè rúbo
Ató fi rúbo
Enìkejìi è bá n bò
Nbgà ó dé kò bá àdìre lára Ato mó
Èsù tí pààrò àdìre ara è
Enìkejì òrun ò bá rajà lówó è mó
Ó nó Òrúpa jégédé
Awo ebá òna
A díá fún Ato
Níjó tí sòwò rojà Èjìgbòmekùn
Tí n lo rèé pón èko
Wón ní ó sá káalè ebo ní ó se
Ato gbébo nbè
Ó rúbo
Rírú ebo
Èèrù àtùkèsù
A wá bÁtp láìkú kanngiri
Àìkú kanngiri là ó wà
Òtúrúpòn Òsé B
Éste es comerciante renombrado que vende y colecciona dinero para él. Ifá le pide
realizar sacrificio tal que su copia celestial no vendría a comprar lo bueno de él en la
tierra. Él debe sacrificar una tela blanca.
Òrúpa jégédé
El sacerdote de la orilla del camino
Adivinación lanzada para Ato
En el día ella estaba comerciando al mercado de Èjìgbòmekùn
Ella iba a vender la papilla dura
Le pidieron que realizara sacrificio
Ato estaba haciendo papilla dura en el mercado de Èjìgbòmekùn
Ella estaba llevando una tela de Àdìre
Ella se puso muy popular
Las personas caminantes de vida siempre vinieron a comprar la papilla de ella
Su copia en el cielo decidió ir y visitar a Ato entonces
Ella quiso ir y comprar la papilla de ella en la tierra
Ellos le dijeron antes de que ella dejara el cielo que Ato se vestiría en Àdìre
Ato durmió entonces
Su sueño era lleno de pesadillas
Ellos le pidieron que sacrificara tela sobre ella
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òfún A
Ifá pé kí eléyìun ó rúbo, ká móo fi mímó bo àwon Irúnmolè. Bí eléyìí bá je Babaláwo,
tòun tí mímo ni kó móo bo Ifáa rè. Ifá pé bó bá n se kinní kan tí ò rójú è, kó se sùúrù
tòrí yóó rójú è. Kó móo wè ní àkókó ìgbà táàá wè; kó móo sùn, móo jí ní gégé táàá jí.
Ifá pé kó wewó wesè kó sì móo bóju kó tóó móo fún òun ní nnkan. Tí bá tí n se eléyìun,
gbogo è ní ó dáa.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ilé ò lónkà mó
Nnkaan wón rò
Ayé wón dáa
N won wá n jó ní wá n yò
Won n yin àwon Babaláwo
Àwon Babaláwo n yin Ifá
Wón ní béè làwon Babaláwo tàwón wí
Olóyìígí lawo Òyígí
Òyígí Awo Òyígí
Awo kéré kèrè kéré
N lawoo gbìrì n gbiri
Awoo gbìrìn n gbíri n lawo Èmìlà alè
Èrín yóbóyóbó n ni tOpó
Èrín wèsìwèsì ni tÒndóko
Dókódókó abèrín sèwèlèsewele
A díá fún Edun tí n borí Olú
Bí tí n bOrí Olú lálé béè ni ò fín
Wón ní ó móo bójú lálé
Kó tóó móó bOrí Olú
A díá fún Irò tí n bòrun Àjùwònlèsì ní kùtùkùtù
N bÒrun Àjùwònlèsì ní kùtùkùtù òwúrò
Òrun Àjùwònlèsì ò gbà
Wón ní kó móo wesè kàsìkàsì àwúrò dànù ní kùtùkùtù
Kó tíí móo bÒrun Àjùwònlèsì
Edún bOrí Olú
Orí Olú fín
Irò bÒrun Àjùwònlèsì
Òrun Àjùwònlèsì wáá gbà yanran gbà yanran bíiná oko
Ìkán ló wálè ló kómo tiè sí
Ìgòngò ló wáá wálè ló kómo tiè sáàtàn
Òrènté ló wá gbobì tán ló pónka
A díá fún Ikì dèèrè
Èyí tí n lo rèé wo Ifá fún Olófin ní mòrun àìkú
A wáá ráwo lónìí
A rí kì
Ifá gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Kóo gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Wáá gbobì kí mòo rájé ní
Sowó dèèrè
Kóo gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Wáá gbobí kí n móo láya
Sowó dèèrè
Kóo gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Wáá gbobì kí n móo bímo
Sowó dèèrè
Kóo gbobì mi ò
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Sowó dèèrè
Wáá gbobì kí n móo kólé
Sowó dèèrè
Kóo gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Wáá gbobì kí n lógbó
Kí n látó
Kí n níre gbogbo
Sowó dèèrè
Kóo gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Gbobì mi lónìí
Gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Gbobì mi ò
Sowó dèèrè
Òtúrúpòn Òfún A
Esta persona se insta para ofrecer el sacrificio con la limpieza y santidad a su Òrìsà. Si
éste es un Babaláwo. Está con la limpieza que él debe ofrecer kola a su Ifá. Él siempre
debe lavar sus manos y piernas antes de ofrecer el kola. Ifá dice que esta persona está
probando sus manos en algo sin éxito. Animan que él persevere porque él tendría pronto
el éxito. Él debe bañarse regularmente, debe dormir y debe despertarse dentro de los
períodos normales.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òfún B
Ayé ó ye eléyìun. Ifá pé bí idán lòún ó se sehun gbogbo fún un. Òpòlopò ìkó òwú lebo
è.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Òtúrúpòn Òfún B
Ifá dice que la vida agradaría a esta persona. Él lograría el éxito como si tal como
magia. Un rollo de cordón es el objeto de sacrificio.
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69
Ifadowole
Ifadowole
PAGE 69