Omiero
Omiero
Omiero
- Obi abata
- Vaina de ataara
- Orogbo
- Oti
- Omi
- Envase grande
IBA IBA
D´IFA FUN BABA ALAKO OKA
OMO A S OKO F´EYE MU JE
WON NI KO MAA A JUBA F´OSO
KO MA JUBA AJE ORUN
KO MA JUBA AWO AKODA
KO MA AJUBA AWO ASEDA
KO MA JUBA GBOGBO IRUNMOLE
KO TO S OHUN GBOGBO TO BA FE SE
A JI, A JUBA BABA IBA A SE
AJI, A JUBA YEYE
AJI, A JUBA AKODA
AJI, AJUBA ASEDA
A JUBA ARABA L´OTU IFE
AJI, A JUBA OLUBIKIN
OLUBIKIN LO KO K´EWE JA
KI IBA TI WA O MA SE FUN WA
KI E JE KO JE FUN WA
A JUBA AWON ATETE DA
TO TI NDA TIRE LALE PEPEEPE
A JUBA, KI E JE KI IBA TIWA O SE FUN WA, ASE
BABALAWO IFA GBADEGA TOKUN “OGBE ATE”
OSAYIN
OLODUMARE
KÍ O MÁA Śọ BABA WA
KÍ O MÁA Śọ ÌYÁ WA
KÍ O MÁA Śọ AYA/ỌKọ WA
KÍ O FI YÈ DÉNÚ
KÍ O FI YÈ DÉKÙN
KÍ O FI YÈ DÉ GBOGBO ARA
ORIKI ESU
ORIKI A OSÚN
Ore yèyè ò!
Ore yèyè ò!
Ore yèyé Òsun ò!
Ore yèyé morò
Òro Yèyé Ó
sòro oOgidi
omiÒsun
pèléOnílé àkòdìÌyá Ìjèsà pèlé oAlómi lóhùnKàárè!
Kúré ò!
Omi ò!
Ota ò!
Ide ò!
Àgbá ò!
ORIKI OSAYIN
ATOOBAJAYE O AFONJA
EWEEELERE OO. EWEEEE. EWEEELERE OO.
EWE NI NSE O BAYI BI. OKO LAYA MI ORUN.
EWEEEE. EWEEELERE OO.
SEEREJOBI EWE TII SOMO ORI IGI. IPIN BAWONYI SOMO AGBIJALE.
EWEEEE. EWEEELERE OO. ASE
El proceso debe ser explicado a Osayin, se le debe pedir que bendiga las ewe.
BABALAWO IFA GBADEGA TOKUN “OGBE ATE”
El babalawo rezara sobre el OROGBO, deberá ser lanzado para hacer la lectura.
Luego debe hacerlo sobre el Obi ABATA para posteriormente lanzarlo y hacer
lectura.
Luego se cortara un pedacito de los extremos del OBI ABATA, las masticará y
luego rociara sobre las hierbas diciendo:
GBA OBI JE
EWE OKO, GBA OBI JE
EWE OKO, GBA OBI JE
GBA ATA JE
EWE OKO, GBA ATA JE
EWE OKO, GBA ATA JE
Se toma una porción de LICOR (OTI) y se sopla sobre las hierbas diciendo:
GBA OTI MU
EWE OKO, GBA OTI MU
EWE OKO, GBA OTI MU
Se toma una porción de agua (omi tutu) y se sopla sobre las hierbas diciendo:
GBA OMI MU
EWE OKO, GBA OMI MU
EWE OKO, GBA OMI MU
ODUNDUN (prodigiosa)
ORIN
BABALAWO IFA GBADEGA TOKUN “OGBE ATE”
ODUNDUN MA NI TEWERU
ODUNDUN MA NI TEWERU
BOBA DAMODUM
MA LE TEWERU
ODUNDUN MA NI TEWERU
TETE-ADAYEBA (Bledo)
BI AGBADO BA YO IRUKERE
KO JE FI LE OMO ELOMIRAN LOWO
A PIN TEELE-TEELE KARI OMO RE
A DIFA FUN ESE KAN SOSO OGBE
TI WON NI KO NI TELE YI PE
EBO NI WON NI KOSE
OUN SI GBEBO NILE TONI
TETE KO MA TELE
TETE TEE RERE
IWO NI ONILE TETE TEE RERE
OGBE ATE
ORIN
TA LONILE TONI
TETE KO MA TE
TETE TEE RERE
SE BIWO LONILE
TETE TEE RERE
OWÚ (Algodón)
ORIN
OKIKAN (JOBO)
AKOKO (CAYENA)
KO RE WA O
AKOKO ELUJU, KORE WA O
AKOKO ALUJU
KOKO (MALANGUILLA)
KO BI LO O
KOKO, KO KO KU LO
KOKO, KO ARUN LO
ETIPON OLA
Mientras que las hierbas son colocadas en un recipiente con agua se dice:
BABALAWO IFA GBADEGA TOKUN “OGBE ATE”
BI MO DURO, BI MO WURE
IRE TEMI KA SAI GBA
BI MO JOKO, BI MO WURE
IRE TEMI KA SAI GBA
ERUN, ERUN
CORO: O O, ERUN
ERUN, ERUN
ERUN K´OLE
ERUN, ERUN
ERUN J´OGBO
ERUN, ERUN
ERUN J´ATO
ERUN, ERUN
ERUN S´ASEYORÍ
ERUN, ERUN
ERUN N´IRE GBOGBO
LAVATORIO