Kunle Ajibade
Ìrísí
Kunle Ajibade | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kàrún 1958 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ | Journalist, editor, writer |
Kunle Ajibade (tí wọ́n bí ní 28 May 1958) jẹ́ akoroyin, olóòtú àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria. Ní ọdún 1995, pẹ̀lú Olusegun Obasanjo, àti àwọn oníròyìn mẹ́ta mìíràn, ni wọ́n fi ẹ̀sùn ọ̀tẹ̀ kàn.[1] [2] Ní ọdún 1998/1999, ó di ọmọ ẹgbẹ́ Feuchtwanger ní Villa Aurora ní Los Angeles. [3]
Ètò-ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ajíbádé gboyèẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Masters nínú ìmọ̀ Literature-In-English láti Obafemi Awolowo University. Ó ti ṣiṣẹ́ bíi akọ̀ròyìn àgbà ní The African Concord, aṣèrànwọ́ olóòtú ní The African Guardian, àti bí olóòtú àgbà ní TheNEWS àti PM News.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Book Review – Jailed for life By Kunle Ajibade" (in en-US). Village Square Forums. Archived from the original on 2017-12-16. https://web.archive.org/web/20171216201108/http://nigeriavillagesquare.com/forum/threads/jailed-for-life-by-kunle-ajibade.469/.
- ↑ "KUNLE AJIBADE: A PROFILE IN COURAGE" (in en). Nigerian Voice. https://www.thenigerianvoice.com/news/28972/kunle-ajibade-a-profile-in-courage.html.
- ↑ "Book Review – Jailed for life By Kunle Ajibade" (in en-US). Village Square Forums. Archived from the original on 2017-12-16. https://web.archive.org/web/20171216201108/http://nigeriavillagesquare.com/forum/threads/jailed-for-life-by-kunle-ajibade.469/.