Ẹ̀bùn Nobel
Ẹ̀bùn Nobel The Nobel Prize | |
---|---|
Bíbún fún | Outstanding contributions in Physics, Chemistry, Literature, Peace, and Physiology or Medicine. The Sveriges Riksbank Prize in Economic Sciences in Memory of Alfred Nobel, identified with the Nobel Prize, is awarded for outstanding contributions in Economics. |
Látọwọ́ | Swedish Academy Royal Swedish Academy of Sciences Karolinska Institutet Norwegian Nobel Committee |
Orílẹ̀-èdè | Sweden, Norway |
Bíbún láàkọ́kọ́ | 1901 |
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ | http://nobelprize.org |
Ẹ̀bùn Nobel (Ẹ̀bùn Nobel ní èdè Gẹ̀̀ẹ́̀si àti Nobelpriset ní ède Sweden Norwegian: Nobelprisen) ní àwọn èbùn odoódún káríayé tí àwọn ìgbìmọ̀ ará Scandinafia ń fún ni fún ìdámọ̀ ìmúlọsíwájú àṣà àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀. Wọ́n jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1895 latowo ara Sweden onímọ̀ ẹ̀kọ́ ẹ̀lá (kẹ́místri) Alfred Nobel, olúṣé dynamite. Àwọn èbún nínú Fisiksi, Kemistri, Ìwòsàn, Litireso, ati Alafia koko je bibun ni 1901. Ebun Sveriges Riksbank ninu ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ Okòwò ní Ìrántí Alfred Nobel jẹ́ dídìmúlẹ́ látọwọ́ Sveriges Riksbank ní ọdún 1968 ó sí kọ́kọ́ jẹ́ bíbùn ní ọdún 1969. Bótilẹ̀jẹ́pẹ́ èyí kìí ṣe ẹ̀bùn Nobel gangan, ìkéde àti ìfifún ré̀ ń sélẹ̀ nígbà kan náà mọ́ àwọn ẹ̀bùn yókù. Ẹ̀bùn kọ̀ọ̀kan jẹ́ dídámọ̀ ní pàápàá fún iṣé wọn.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
- ↑ Shalev, Baruch Aba (2005). p. 8.